# nb/xpdObHebZ6gU.xml.gz
# yor/xpdObHebZ6gU.xml.gz


(src)="1"> Hallo
(trg)="1">

(src)="2"> Dagens spørsmål kommer fra San Francisco , California .
(trg)="2"> Ìbéèrè t" ònìí wá láti San Francisco , California .

(src)="3"> Blind femåring spør , " Hvor pålitelig er siden : søket , og hvorfor er antallet av og til annerledes fra side en til side to ? "
(trg)="3"> Afọ́jú ọmọ ọdún márùn- ún béèrè , " Báwo ni ìgbẹ́kẹ̀lé kólọ̀ọ̀nù , ìṣèbéèrè àti kíni ìdí tí àpapọ̀ ònkà ìtàkùn àgbà- ńlá ayé ṣe ma ń yípadà láti ojú- ìwé kìíní síkejì ? "

(src)="4"> Jeg kunner ikke svare for side : søket .
(trg)="4"> Mi ò ní fi sọ ọ́ n í ti ìṣèbéèrè kólọ̀ọ̀nù ìtàkùn !

(src)="5"> Istedenfor , ville jeg snudd og lagt fokus på resultats anslag .
(trg)="5"> Kàkà bẹ́ẹ̀ , mà á f' ọkàn sí ìfojúṣírò èsì .

(src)="6"> Noen ting du bør vite .
(trg)="6"> Torí bẹ́ẹ̀ ó ní nǹkan díẹ̀ láti mọ̀ .

(src)="7"> For det første , om du ikke har lagt merke til det , bør du legge merke til at resultats anslagene bare er nøyaktig mot tre siffer .
(trg)="7"> Ìkìíní , bí o kò bá ṣe àkíyèsí , ó yẹ kí o mọ̀ pé ìfojúṣírò èsì ma ń ṣe déédé bíi dígítì mẹ́ta .

(src)="8"> De er antagelser .
(trg)="8"> Torí ìfojúṣírò ni .

(src)="9"> Mens vi ser etter resultater , må vi trekke en grense , nå har vi nok til førstesiden og vi vil se hvor langt vi har gått gjennom oppslagslisten mengden data vi har derfor kan vi gjøre et anslag om at det er så mange resultat igjen .
(trg)="9"> Bí a ṣe ń wá ìṣèbéèrè , nígbà mìíràn a ma ní , Ó dára , èyí tí a ní ti tó wa fún ojú- ìwé àkọ́kọ́ , a ó sì ríi b 'ó ti rí a yẹṣẹ́ẹ wa wò -- iye data tí a ní , nítorí náà -- nítorí náà , a lè ṣe ìfojúṣírò iye èsì tí ó kù nílẹ̀ẹ .

(src)="10"> Når du klikker over på side to , går du plutselig dypere .
(trg)="10"> Nísìyín bí o bá klíkì ojú- ìwé kìíní sí kejì , lójijì ni o ti ń jìn sínúu rẹ̀ désàlẹ̀ .

(src)="11"> Og du har et bedre anslag eller du vil ha et
(src)="12"> litt annet anslag , fordi du begynner å se ikke bare litt gjennom alle de dokumentene , du begynner faktisk å gå dypere og dypere .
(trg)="11"> A fún ọ ní' fojúṣírò t´ó dáa jù tàbí ìfojúṣírò t 'ó yàtọ̀ díẹ̀ , nítorí o ti bẹ̀rẹ̀ láti má wo díẹ̀ nínú gbogbo ìwé o ti ń jìn sínúu rẹ̀ gan- an .

(src)="13"> Så det er ganske vanlig for resultats anslagene våres å forandre seg fra side en ti side to , som oftest blir de mer nøyaktig .
(trg)="12"> Nítorí bẹ́ẹ̀ ó wọ́pọ̀ kí èsì ìfojúṣírò yípadà láti ojú- ìwé kìíní síkejì , tí yóò mu ṣe déédé .

(src)="14"> Så det er ikke en vanlig faktor i siden : søket .
(src)="15"> Det er vanligvis en faktor i at vi graver dypere gjennom dataene våres , som et resultat , har vi et bedre eller i det minste et annerledes anslag på antal resultat .
(trg)="13"> Torí èyí kì í ṣe nítorí kólọ̀ọ̀nù ìṣèbéèrè ìtàkùn . torí a má ńwọ inú rẹ̀ lọ désàlẹ̀ nípasẹ̀ data wa , látàrí bẹ́ẹ̀ , a ní ìyàtọ̀ ìfojúṣírò t 'ó dára jù tàbí ó kéré jù ìyàtọ̀ ìfojúṣírò èsì t 'ó wà .

(src)="16"> Ha det !
(trg)="14"> Lọ sí google . com/ webmasters