# es/0rWGviAAKkpk.xml.gz
# yor/0rWGviAAKkpk.xml.gz
(src)="1"> & gt ; & gt ; & gt; Maile Ohye :
(trg)="1"> & gt ; & gt ; & gt; Maile Ohye :
(src)="2"> Hola , soy Maile Ohye .
(trg)="2"> E kaabo , Oruko mi ni Maile Ohye .
(src)="3"> Soy una desarrolladora principal de programas tecnológicos en Google .
(src)="4"> Llevo en
(src)="5"> Google desde 2005 trabajando con nuestros equipos de búsqueda y herramientas webmaster .
(trg)="3"> Mo je defelopa ati adari awon eto kookan ni ile- ise google . mo ti wa ni ile- ise google lati odun 2005 mo si n sise pelu awon akegbe mi ti won n mojuto ero ti a fi se iwadi ati ti a fi se eto ayelujara .
(src)="6"> Pero si yo fuera un consultor para su empresa , aquí estarían todos los consejos que daría en menos de 10 minutos .
(trg)="4"> Sugbon ti mo ba je eni ti a n ke pe fun ona abayo fun ise ti e fe bere , eyi ni imoran ti maa fun yin ni iseju mewa
(src)="7"> El objetivo de esta charla es para empresas que tienen su principal contenido por debajo de unas 50 páginas .
(trg)="5"> Oro yii wa fun awon ile ise ti akosile on ko to oju- ewe aadota .
(src)="8"> Para aquellos sitios que buscan al rango de miles de palabras no relacionadas , como un sitio de comercio electrónico o una agencia de noticias , puede que desee invertir más tiempo con SEO .
(trg)="6"> Fun awon ibudo ayelujara ti o fe wa iru awon oro akanse ti ko baramu bi ibudo eto oro aje tabi eka iroyin , e o nilo akoko ti ju eyi lo .
(src)="9"> Mi objetivo para esta charla es darle los fundamentos de la manera más eficiente posible y para ayudarlo a sentirse seguro de que no está haciendo algo totalmente erróneo relacionado con las búsquedas , y por último , facilitar los indicadores para obtener más información .
(trg)="7"> Awon ohun ti mo fe soro le lori ni lati pese ipile ni ona ti o peye julo lati ran yin lowo ati lati mu da yin loju wipe e ko se ohun ti o buru patapata nipase ohun ti e n wa ati lati fi ona han yin fun alaye siwaju sii .
(src)="10"> Lo primero que hacer con su dominio es decidir si usted desea que los visitantes vean la versión punto , punto , punto o la versión no punto , punto , punto .
(trg)="8"> Ohun akoko ti e gbodo se pelu ibudo ayelujara yin ni wipe ki e pinu boya e fe ki awon alejo ki won rii gege bi o se wa tabi ki won ri eda ohun ti o wa nibe