# sw/2018_12_kwanini-serikali-za-afrika-zinapinga-na-uhuru-wa-vyombo-vya-habari-na-kutoa-maoni-inawezekana-sababu-ni-nguvu-kubwa-nyuma-yake_.xml.gz
# yo/2018_12_28_115_.xml.gz


(src)="1.1">Kwanini Serikali za Afrika Zinapinga na Uhuru wa Vyombo vya Habari na Kutoa Maoni?
(trg)="1.1"> Kí ló dé tí ìjọba Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ ń f 'òfin de ọ ̀ rọ ̀ sísọ orí-ayélujára ?

(src)="1.2">Inawezekana Sababu ni Nguvu Kubwa Nyuma Yake
(trg)="1.2"> Nítorí wọ ́ n bẹ ̀ rù agbára rẹ ̀ .

(src)="1.3">Wanafunzi wa Chuo Kikuu cha Haromaya nchini Ethiopia wakionesha alama ya kupinga serikali.
(trg)="1.3"> Akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ Ifásitì Haromaya ní Ethiopia ń fi àmì ìtako ìjọba hàn .

(src)="1.4">Picha imeenea kwenye mitandao ya kijamii.
(trg)="1.4"> Àwòrán tí a pín lórí ẹ ̀ rọ-alátagbà .

(src)="2.2">Kisheria name kimasharti ya kiuchumi, gharama ya kuzungumza imepanda barani humo.
(trg)="2.1"> Ọ ̀ rọ ̀ sísọ lórí ayélujára ti ń rí ìfúnpa láti ọwọ ́ ìjọba díẹ ̀ díẹ ̀ .

(src)="4.1">Cameroon, Tanzania, Uganda, Ethiopia, Nigeria, na Benin zikishuhudia kufungwa kwa mitandao, kuanzishwa kwa Kodi kwa wanablogu na watumiaji wa mitandao ya Kiwami sambamba na kukamatwa kwa waandishi wa habari.
(trg)="4.1"> Cameroon , Tanzania , Uganda , Ethiopia , Nigeria , àti Benin ti ní Ìtìpa Ẹ ̀ rọ-ayélujára , ìjọba ti fi owó-orí lé lílo búlọ ́ ọ ̀ gù àti ẹ ̀ rọ-alátagbà , wọ ́ n sì ti fi ọwọ ́ ṣìgún òfin mú oníròyìn .

(src)="4.2">Wafanyakazi wa vyombo vya habari wakifungwa kwa madai ya kuchapisha makala yaliyoandikwa taarifa za uongo ambayo hupelekea kuvujishwa kwa siri za serikali au matukio ya ugaidi.
(trg)="4.2"> Òṣìṣẹ ́ ìròyìn àti àwọn ọmọ-ìlú ti di èrò àtìmọ ́ lé lórí ẹ ̀ sùn àtẹ ̀ jáde " ìròyìn irọ ́ " títí kan ìkóròyìn ìkòkọ ̀ ìlú sí etí ìgbọ ́ ẹgbẹ ́ afẹ ̀ míṣòfò .

(src)="6.1">Nchi nyingi zina amri na sheria ambazo zinatetea haki ya uhuru wa kuongea.
(trg)="6.1"> Ọ ̀ pọ ̀ orílẹ ̀ -èdè ló ní àwọn òfin àti àbádòfin tí ó fún ọmọ ènìyàn ní ẹ ̀ tọ ́ sí òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ .

(src)="6.2">Nigeria, ikitajwa kama mfano, kipengele cha Uhuru wa Habari kinatetea haki ya wananchi kudai taarifa kutoka kwa shirika lolote la kiserikali.
(trg)="6.2"> Ní Nàìjíríà , fún àpẹẹrẹ , Àbádòfin Òmìnira Ọ ̀ rọ ̀ fún ọmọ ìlú ní òmìnira láti béèrè fún ìwífun lọ ́ wọ ́ àjọ ìjọba .

(src)="6.3">Sehemu ya 22 kwenye katiba ya mwaka 1999 inatoa uhuru kwa vyombo vya habari na Sehemu ya 39 ikitilia mkazo kwamba “kila mtu ana haki ya kuongea, ikiwem uhuru wa kushikilia na kupokea taarifa na kutoa mawazo na taarifa bila kuingiliana …”
(trg)="6.3"> Abala 22 ìwé òfin ọdún 1999 pèsè fún ẹ ̀ tọ ́ òmìnira ìròyìn àti Abala 39 fi lélẹ ̀ wípé " gbogbo ènìyàn ni ó ní ẹ ̀ tọ ́ sí òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ , títí kan òmìnira láti gbá ìròyìn mú àti gba ọgbọ ́ n àti ìwífun láì sí ìdíwọ ́ ... "

(src)="7.1">Bado, Nigeria iliweka sheria nyingine ambazo zilitoa mamlaka ya kukana sheria zilizotajwa hapo awali.
(trg)="7.1"> Síbẹ ̀ , Nàìjíríà tí tẹ àwọn òfin kan tí ó tẹ orí àwọn ẹ ̀ tọ ́ òkè yìí bọlẹ ̀ .

(src)="9.2">Serikali na mawakala wao wakitumia hili kufunika haki ya uhuru wa kuongea.
(trg)="9.2"> Ìjọba àti àwọn àjọ rẹ ̀ máa ń sábà fi èyí ṣe bójúbójú fún ìtẹríbọlẹ ̀ òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ .

(src)="11.2">Usiteseke katika hali ya ukimya — endelea kuongea
(trg)="10.1"> Ta ni ẹni tí ó ń sọ bóyá ọ ̀ rọ ̀ kan jẹ ́ àfojúdi ?

(src)="12.1">Kwa uzoefu wa wanablogu wa Ethiopia maarufu kama wanablogu wa Zone9 nchini Ethiopia wanatoa mfano huu hapa wenye nguvu kwelikweli.
(trg)="10.4"> Kí ló dé tí Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ kò ní ẹ ̀ tọ ́ láti ṣẹ ̀ gẹ ́ gẹ ́ bí ẹ ̀ ka tí ó ṣe pàtàkì nínú òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ ?

(src)="13.1">Mnamo mwaka 2014, waandishi tisa wananchi wa Ethiopia walifungwa jela na kuteswa kwa sababu ya kushiriki kwao kwenye mradi wa blogu ambapo waliandika kuhusu ukiukwaji wa haki za binadamu uliokua ukifanywa na serikali iliyopita nchini humo Ethiopia, kuthubutu kwao kuandika ukweli uliowahusu wenye nguvu.
(trg)="13.1"> Ní ọdún 2014 , àwọn òǹkọ ̀ wé ọmọ bíbí Ethiopia mẹ ́ sàn-án lọ sí ẹ ̀ wọ ̀ n àti jìyà oró látàrí iṣẹ ́ àjọṣepọ ̀ tí wọ ́ n jọ kọ nípa ìtẹsẹ ̀ àgẹ ̀ rẹ ̀ sí ẹ ̀ tọ ́ ọmọ-ènìyàn ìjọba àná ìlú Ethiopia , kí òótọ ́ ó di mímọ ̀ .

(src)="14.1">Wanachama wa Zone9 Mahlet (kushoto) na Zelalem (kulia) wakifurahia kuachiwa huru kwa Befeqadu Hailu (wa pili kutoka kulia, mwenye kitambaa shingoni) mwezi Oktoba 2015.
(trg)="14.1"> Àwọn ọmọ ẹgbẹ ́ Zone9 Mahlet ( òsì ) àti Zelalem ( ọ ̀ tún ) ń dun 'nú fún ìdásílẹ ̀ lẹ ́ wọ ̀ n Befeqadu Hailu ( ẹnìkejì láti ọwọ ́ òsì , pẹ ̀ lú sícáàfù ) ní oṣù kẹwàá ọdún 2015 .

(src)="14.2">Picha umewekwa kwenye mtandao wa Twita na Zelalem Kiberet.
(trg)="14.2"> Orí Twitter ni Zelalem Kiberet ti pín àwòrán yìí .

(src)="15.2">Jomanex Kasaye, ambaye alifanya kazi na kikundi hapo awali hadi kufikia wakati ambapo wenzake wote walipokamatwa ( lakini yeye hakukamatwa) nae alipata wasaha wa kuhudhuria.
(trg)="15.2"> Jomanex Kasaye , ẹni tí ó ti bá ẹgbẹ ́ náà ṣiṣẹ ́ kí àtìmọ ́ lé ó tó ṣẹlẹ ̀ ( àmọ ́ tí a kò fi àṣẹ mú ) náà kò gbẹ ́ yìn níbi àpérò .

(src)="17.2">Pande zote kuu nne za dunia ziliangua kilio kikubwa kuwataka serikali ya Ethiopia iwaweke huru waandishi hao waliofahamika kama Zone9 bloggers.
(trg)="17.2"> Láti orígun mẹ ́ rẹ ̀ ẹ ̀ rin àgbáyé , igbe ńlá ni ó gba àwọn akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 sílẹ ̀ lọ ́ wọ ́ ìjọba ilẹ ̀ Ethiopia .

(src)="18.2">Kwenye kikao cha jopo, n their panel session, walitoa shukurani zao kwa kutambua mchango wa kampeni zilizofanywa na Global Voices kuwaweka hai.
(trg)="18.2"> Ní ètò ìtàkùrọ ̀ sọ wọn , wọ ́ n gbé orí yìn fún ìpolongo Ohùn Àgbáyé tí ó ṣe iṣẹ ́ ribiribi tí ó mú àwọn wà láyé .

(src)="19.1">Berhan Taye, msimamizi wa jopo aliwataka wanakikundi hao waliokamatwa kuelezea baadhi ya mambo waliokutana nayo walipokua wamekamatwa.
(trg)="19.1"> Berhan Taye , atọ ́ kùn ìtàkùrọ ̀ sọ , bi ẹgbẹ ́ yìí ní ìbéèrè ìrírí wọn ní inú túbú .

(src)="19.2">Na walipoanza kueleza taa zilizokua zikiwaka jukwaani zilizimwa.
(trg)="19.2"> Bí wọ ́ n ti ṣe sọ , iná amọ ́ roro ìtàgé wálẹ ̀ díẹ ̀ .

(src)="19.3">Hivyo sauti zao zenye nguvu zilitanda ukumbini.
(trg)="19.3"> Ohùn-un wọn mú kí iyàrá ètò pa lọ ́ lọ ́ .

(src)="21.1">Atnaf Berhane akikumbuka moja kati ya mateso aliyopata mpaka saa nane ya usiku na kuendelea baada ya kupewa masaa machache kulala.
(trg)="22.1"> Ọ ̀ kan lára àwọn agbófinró tí ó mú Zelalem Kibret ti fi ìgbà kan rí jẹ ́ akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ Kibret ní Ifásitì tí ó ti ń ṣe iṣẹ ́ olùkọ ́ .

(src)="24.1">Wanablogu wa Zone9 wakiwa pamoja jijini Addis Ababa, 2012.
(trg)="24.1"> Àpapọ ̀ Akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 ní Addis Ababa , ní ọdún 2012 .

(src)="24.2">Kutoka kushoto: Endalk, Soleyana, Natnael, Abel, Befeqadu, Mahlet, Zelalem, Atnaf, Jomanex.
(trg)="24.2"> Láti ọwọ ́ ọ ̀ tún : Endalk , Soleyana , Natnael , Abel , Befeqadu , Mahlet , Zelalem , Atnaf , Jomanex .

(src)="24.3">Picha ya Endalk Chala.
(trg)="24.3"> Endalk Chala ni ó ni àwòrán .

(src)="26.1">Bado, waandishi hao walirejea kwenye maana halisi ya uzalendo kwa maneno na matendo yao.
(trg)="26.1"> Síbẹ ̀ , akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 ṣe àtúnlò ìfẹ ́ -ìlú-ẹni nínú ọ ̀ rọ ̀ àti ìṣe .

(src)="27.2">Tanguia pale mwindaji alipojifunza kulenga bila kukosea, na ndege pia amejifunza kuruka bila kutua.
(trg)="27.2"> Níwọ ̀ n ìgbà tí òde ti já ọgbọ ́ n àtamátàsè , ẹyẹ Eneke náà ti kọ ́ fífò láì bà .

(src)="28.1">Wanaharakati walio mstari wa mbele kutetea hili kwenye nchi za chini ya Jwangwa la Sahara Afrika na nyinginezo duniani hawawezi kustahimili kufanya kazi chini chini au bila sauti wakiwa wamechanganyikiwa na kushindwa.
(trg)="28.1"> Àwọn ajàfúnẹ ̀ tọ ́ tí ó ń lé iwájú nínú òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ ní ìlú-Gúúsù-Aṣálẹ ̀ -Sàhárà àti káríayé kò gbọdọ ̀ ṣe aláì máà wá wọ ̀ rọ ̀ kọ ̀ fi ṣ 'àdá lórí ọ ̀ ràn yìí .