# ru/2018_12_18_79703_.xml.gz
# yo/2018_12_23_103_.xml.gz


(src)="1.1"> Полностью женский экипаж самолета войдет в историю Мозамбика
(trg)="1.1"> Òṣìṣẹ ́ inú ọkọ ̀ òfuurufú olóbìrin nìkan wọ ìwé ìtàn ní Mozambique

(src)="1.2"> Первый женский экипаж в Мозамбике .
(trg)="1.2"> Ikọ ̀ awakọ ̀ òfuurufú olóbìrin àkọ ́ kọ ́ irúu rẹ ̀ ní Mozambique | A lo àwòrán pẹ ̀ lú àṣẹ láti ọwọ ́ Meck Antonio .

(src)="4.1"> Представленные в статье женщины – члены организации MEX , первоначально созданной в качестве специального оперативного отдела авиакомпании LAM Mozambique Airlines .
(trg)="4.1"> Àwọn obìrin wọ ̀ nyí wà nínú ẹgbẹ ́ MEX , ilé-iṣẹ ́ tí a dá sílẹ ̀ gẹ ́ gẹ ́ bíi Ẹ ̀ ka Iṣẹ ́ Àkànṣe LAM — Linhas Aéreas de Moçambique .

(src)="4.2"> В 1995 году организация начала работать как самостоятельная авиакомпания Mozambique Express .
(trg)="4.2"> Ní 1995 , ó bẹ ̀ rẹ ̀ iṣẹ ́ bíi ilé-iṣẹ ́ ọkọ ̀ òfuurufú aládàáni , Mozambique Express .

(src)="5.2"> Исторический день – полностью женский экипаж .
(trg)="5.2"> ỌJỌ ́ ÌTÀN - Ikọ ̀ ọkọ ̀ òfuurufú TM112 / 3 MPM-VPY-MPM ( Maputo-Chimoio-Maputo )

(src)="7.1"> Поздравляю MEX !
(trg)="6.1"> MEX kú oríire !

(src)="8.1"> Поздравляю членов экипажа !
(trg)="7.1"> Ikọ ̀ ẹ kú oríire !

(src)="9.1"> Поздравляю Мозамбик !
(trg)="8.1"> Mozambique , kú oríire !

(src)="9.2"> Больше женщин во все сферы деятельности .
(trg)="8.2"> Fún ọ ̀ pọ ̀ lọpọ ̀ obìrin nínú iṣẹ ́ gbogbo .

(src)="9.3"> Общественный активист Мауро Брито добавил , что женщинам следует гордиться тем , что « они представлены в различных сферах деятельности » :
(trg)="8.3"> Àjàfúnẹ ̀ tọ ́ ìkẹ ́ gbẹ ́ Mauro Brito sọ ní tirẹ ̀ wípé obìrin gbọ ́ dọ ̀ ní ìgbéraga " nígbàtí bá jẹ ́ aṣojú nínú iṣẹ ́ gbogbo " :

(src)="9.5"> Я думаю , что тем женщинам , которые считали , что данная профессия подходит лишь мужчинам , теперь следует гордиться .
(trg)="8.5"> Mo rò ó wípé àwọn obìrin tí ó ronú láti ṣe iṣẹ ́ tí ọkùnrin máa ń ṣe , gbọdọ ̀ gbéraga .

# ru/2018_12_28_79886_.xml.gz
# yo/2018_12_23_99_.xml.gz


(src)="1.3"> Изображения с Weibo .
(trg)="1.1"> Ìpolongo ìtakò Kérésìmesì ìlú China mú yíyan àjọyọ ̀ le fún ọmọ-ìlú

(src)="2.1"> .
(trg)="1.3"> Àwòrán láti Weibo .

(src)="4.1"> В 2017 году Центральный комитет Коммунистической партии Китая и Государственный совет КНР издали документ « Меры по разработке проектов , направленные на развитие и продвижение традиционной культуры Китая » .
(trg)="3.1"> Ní ọdún 2017 , ìgbìmọ ̀ àgbà àti àjọ ìpínlẹ ̀ lábẹ ́ ẹgbẹ ́ olóṣèlú Communist ìlú China kọ ìwé àṣẹ kan tí a pe àkọlée rẹ ̀ ní " Ìmọ ̀ ràn lórí imúdiṣíṣẹ iṣẹ ́ ìgbélárugẹ àti ìdàgbà àṣà ìbílẹ ̀ China dé ibi gíga " .

(src)="4.2"> В документе описываются культурные проекты , достойные возрождения , среди которых такие фестивали , как китайский Новый год и Праздник фонарей .
(trg)="3.2"> Wọ ́ n la àwọn àkànṣe iṣẹ ́ ìsọjí àṣà bíi Ọdún Òṣùpá Tuntun àti Àjọ ̀ dún Àtùpà sílẹ ̀ , láì pa ìyìókù tì , gẹ ́ gẹ ́ bí ìpàgọ ́ tí ó jẹ mọ ́ ti àṣà tí ó lákaakì .

(src)="5.1"> Чтобы претворить в жизнь данные меры , власти Китая запустили несколько идеологических кампаний , направленных на борьбу с иностранными праздниками .
(trg)="4.1"> Kí òfin yìí lè di àmúṣẹ , ìjọba China ti ṣe ìfilọ ́ lẹ ̀ àwọn ètò ìpolongo kéékèèké mélòó kan fún ìkọ ̀ yìn sí àwọn ayẹyẹ tí kì í ṣe ti ìbílẹ ̀ China .

(src)="5.2"> В этом году незадолго до Рождества китайские чиновники потребовали убрать все рождественские украшения с улиц и витрин в городе Ланфан ( провинция Хэбэй ) .
(trg)="4.2"> Ọdún nìín , ọjọ ́ díẹ ̀ sí Kérésìmesì , ìjọba ní àwọn ìlú ńlá bíi Langfang , ní agbègbèe Hebei , ti pa á ní àṣẹ fún ìsọ ̀ gbogbo láti yọ ẹ ̀ ṣọ ́ ọdún Kérésìmesì kúrò lójú títí àti fèrèsé .

(src)="7.1"> Скриншот ленты новостей Weibo , посвящённых комментариям против западного праздника .
(trg)="7.1"> Ònlo Weibo Long Zhigao ya àwòrán ìròyìn orí WeChat ti rẹ ̀ ní orí Weibo ní ìfihàn àríyànjiyàn .

(src)="8.2"> Заголовки ленты : 1 .
(trg)="7.2"> Kókó ìròyìn àkọ ́ kọ ́ 1 .

(src)="8.3"> Скоро наступит западный праздник .
(trg)="7.3"> Àjọ ̀ dún Òyìnbó ń bọ ̀ lọ ́ nà dẹ ̀ dẹ ̀ .

(src)="8.4"> Праздновать или не праздновать , вот в чём вопрос .
(trg)="7.4"> Kí a ṣe àjọyọ ̀ àbí kí á máà ṣe é , ìbéèrè ni ìyẹn .

(src)="8.5"> 2 .
(trg)="7.5"> 2 .

(src)="8.6"> Я китаец и не отмечаю западные праздники .
(trg)="7.6"> Ọmọ China ni mí n kò sì kí ń ṣe àjọyọ ̀ Òyìnbó .

(src)="8.7"> 3 .
(trg)="7.7"> 3 .

(src)="8.8"> Скажите « нет » проведению западных праздников в школах .
(trg)="7.8"> Sọ pé rárá fún ìṣàjọyọ ̀ àjọ ̀ dún Òyìnbó nínú ọgbà ilé-ìwé .

(src)="8.9"> 4 .
(trg)="7.9"> 4 .

(src)="8.10"> Государственная партия запретила западные праздники .
(trg)="7.10"> Ẹgbẹ ́ òṣèlú-ìpínlẹ ̀ ti kọ ẹ ̀ yìn sí àjọ ̀ dún Òyìnbó .

(src)="8.11"> Проведение праздников теперь относится к политическим вопросам .
(trg)="7.11"> Àjọyọ ̀ àjọ ̀ dún ti wa di ọ ̀ rọ ̀ ìṣèlú .

(src)="9.1"> Запрет распространяется на празднование не только Рождества , но и Дня святого Валентина , Пасхи и Хэллоуина .
(trg)="8.1"> Láfikún-un Kérésìmesì , àkàsílẹ ̀ àwọn àjọ ̀ dún Òyìnbó kò yọ Àyájọ ́ Ọjọ ́ Olólùfẹ ́ , Àjíǹde àti Halowíìnì , àti bẹ ́ ẹ ̀ bẹ ́ ẹ ̀ lọ sí ẹ ̀ yìn .

(src)="9.2"> Большинство комментаторов называют эти фестивали « вторжением в китайскую культуру » или « унижением нации » .
(trg)="8.2"> Ọ ̀ pọ ̀ lọpọ ̀ ènìyàn ni ó ka àjọ ̀ dún sí " ìgbógunti àṣà " tàbí " ìrẹ ̀ sílẹ ̀ ìlú " .

(src)="10.1"> Например , в одном из наиболее популярных комментариев говорится :
(trg)="9.1"> Fún àpẹẹrẹ , ọ ̀ kan tí ó ràn ká bí ìgbà tí iná bá ń jó pápá inú ọyẹ ́ sọ wípé :

(src)="10.2"> Первый председатель КНР Мао Цзэдун спас многих людей от невзгод .
(trg)="9.6"> Alága àkọ ́ kọ ́ Ìlú-tí-kò-fi-ọba-jẹ ti China Mao Zedong ti yọ àwọn ènìyàn nínú ìṣòro .

(src)="10.3"> Мы должны сделать его день рождения китайским Рождеством .
(trg)="9.7"> A gbọdọ ̀ sọ ọjọ ́ ìbíi rẹ ̀ di Kérésìmesì China .

(src)="10.4"> Откажитесь от западных праздников .
(trg)="9.8"> Gbé ìgbésẹ ̀ kí o kọ àjọ ̀ dún Òyìnbó .

(src)="10.5"> Однако некоторые пользователи Weibo считают такие аргументы нелогичными .
(trg)="9.9"> Àmọ ́ àwọn ènìyàn kan lórí Weibo kò rí ọ ̀ rọ ̀ ọlọgbọ ́ n kankan nínú àríyànjiyàn wọ ̀ nyí .

(src)="10.6"> Один из комментаторов сказал :
(trg)="9.10"> Ẹnìkan sọ pé :

(src)="10.7"> Когда на Западе празднуют китайский Новый год , китайцы гордятся этим и расценивают это как возрождение традиционной китайской культуры ...
(trg)="9.11"> Bí àwọn Òyìnbó bá ń ṣe àjọyọ ̀ Ọdún Òṣùpá Tuntun , àwọn aráa China á gbéraga wọ ́ n á sì rí èyí gẹ ́ gẹ ́ bí ìdàgbà ìsọjí àṣà ìbílẹ ̀ China ...

(src)="10.8"> Но когда китайцы отмечают западные праздники , почему это считается культурным вторжением ?
(trg)="9.12"> Bí àwọn aráa China bá ṣe àjọyọ ̀ àjọ ̀ dún Òyìnbó , kí ni ìdí tí a fi kà wọ ́ n sí ìgbógunti àṣà ?

(src)="10.9"> Молодёжь отмечает эти праздники с целью повеселиться .
(trg)="9.13"> Àwọn ọ ̀ dọ ́ máa ń ṣe àjọyọ ̀ àjọ ̀ dún Òyìnbó nítorí àríyá àti fún ayọ ̀ .

(src)="10.10"> Празднества стимулируют потребление , что в этом плохого ?
(trg)="9.14"> Àwọn àjọ ̀ dún wọ ̀ nyí lè mú ìkóúnjẹjẹ gbòòrò , kí ni ó burú nínú ìyẹn ?

(src)="11.2"> Зачем ?
(trg)="10.2"> Fún kí ni ?

(src)="11.3"> Социальное давление , самоцензура
(trg)="10.3"> Ẹgbẹ ́ kíkó , ìkóraẹni-níjàánu

(src)="11.4"> Поток комментариев против Рождества в социальных сетях заставил некоторых пользователей соцсетей заниматься самоцензурой .
(trg)="10.4"> Àgbàrá òdì ọ ̀ rọ ̀ sí Kérésìmesì ti ṣàn gba orí ẹ ̀ rọ-alátagbà ó sì ti mú kí àwọn òǹlò kan ó kó ara wọn ní ìjánu .

(src)="11.5"> Пользователь Weibo выразил недовольство ситуацией :
(trg)="10.5"> Ònlo Weibo kan fi ẹ ̀ hónú hàn :

(src)="11.6"> Скоро наступит Рождество .
(trg)="10.6"> Kérésìmesì ń bọ ̀ lọ ́ nà dẹ ̀ dẹ ̀ .

(src)="11.7"> Мой круг друзей разделился на противников и сторонников проведения западного праздника .
(trg)="10.7"> Ní agbo ọ ̀ rẹ ́ ẹ wa , àgọ ́ alòdìsí àjọ ̀ dún Òyìnbó àti alòdìsí alòdìsí àjọ ̀ dún Òyìnbó ń ṣe àríyànjiyàn .

(src)="11.8"> Хочет ли кто-то его праздновать или нет — личное решение каждого , почему люди заставляют остальных соглашаться с ними ?
(trg)="10.8"> Kò kan ẹnikéni bóyá èèyàn féràn àjọyọ ̀ tàbí kò fẹ ́ , kí ni ó dé tí àwọn ènìyàn ṣe fẹ ́ ràn láti máa fi túláàsì mú ẹlòmíràn gba èròńgbà ti wọn ?

(src)="11.10"> Те же , кто занимает нейтральную позицию , ради создания баланса должны встать на противоположную сторону .
(trg)="10.10"> Fún àwa tí a wà láàárín , kí a ba mú un dọ ́ gba , a ní láti dúró sí ẹ ̀ gbẹ ́ kejì .

(src)="13.1"> Некоторые пользователи Weibo поделились уведомлениями , которые раздали школьникам .
(trg)="12.1"> Àwọn òǹlo Weibo kan ti pín ìkìlọ ̀ ilé-ìwé ti a fún akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ .

(src)="13.2"> Одно из уведомлений ( справа ) ссылается на документ с « Указаниями » и призывает учителей и студентов отказаться от отмечания праздников в соответствии с западными традициями .
(trg)="12.2"> Ọ ̀ kan nínú ìkìlọ ̀ náà ( ọ ̀ tún ) ń tọ ́ ka sí òfin " Ìmọ ̀ ràn " ó sì rọ olùkọ ́ àti akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ láti kọ àyájọ ́ tí ó fi ara jọ ti Òyìnbó sílẹ ̀ .

(src)="15.1"> Одна из мам удивилась , когда её ребёнок отказался принять рождественский подарок .
(trg)="14.1"> Ìyàlẹ ́ nu ni ó jẹ ́ fún ìyá kan nígbàtí ọmọọ rẹ ̀ kọ ẹ ̀ bùn Kérésìmesì .

(src)="15.2"> Она поделилась на Weibo :
(trg)="14.2"> Ìyá kọ sórí Weibo :

(src)="15.3"> Мама : Малыш , что хочешь на Рождество ?
(trg)="14.3"> Ìyá : Ọmọ mi , ẹ ̀ bùn wo lo fẹ ́ fún Kérésìmesì ?

(src)="16.1"> Ребёнок : Я не буду отмечать западные праздники .
(trg)="15.1"> Ọmọ : Èmi ò ní ṣe àjọyọ ̀ àjọ ̀ dún Òyìnbó kì í ṣe àjọ ̀ dún ìlúu China .

(src)="16.2"> Рождество не традиционный китайский праздник .
(trg)="16.1"> Ó dáa , dájúdájú onígbọràn ọmọ ẹgbẹ ́ òṣèlú àti àwọn ará ìlú ni ọ ́ .

(src)="17.1"> Хорошо , ты и правда ребёнок , преданный Партии и Народу .
(trg)="16.2"> Síbẹ ̀ , àwọn akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ ilé-ẹ ̀ kọ ́ gíga ṣe àròjinlẹ ̀ .

(src)="17.2"> Тем не менее , старшеклассники и студенты колледжей оказались более критичны в этом вопросе .
(trg)="16.3"> Akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ kan ní ìbéèrè lórí òfin ilé-ìwé lórí Weibo :

(src)="17.4"> В школах запретили развешивать рождественские украшения и обмениваться подарками , тем самым протестуя против проведения западных праздников .
(trg)="16.4"> Ilé-ìwé ti gbé ẹsẹ ̀ lé ìṣẹ ̀ ṣọ ́ ọ Kérésìmesì nínú ọgbà ó sì ti sọ pàṣìpàrọ ̀ ẹ ̀ bùn di èèwọ ̀ ní ìpolongo ìtako àjọ ̀ dún Òyìnbó .

(src)="17.6"> Некоторые решили праздновать Рождество втайне .
(trg)="16.6"> Àwọn kan ti yan ìṣàjọyọ ̀ àjọ ̀ dún náà ní ìkọ ̀ kọ ̀ .

(src)="17.7"> Пользователь Weibo говорит :
(trg)="16.7"> Òǹlo Weibo kan sọ :

(src)="17.8"> Компания запретила отмечание западных праздников .
(trg)="16.8"> Ilé-iṣẹ ́ ti sọ ayẹyẹ àjọyọ ̀ àjọ ̀ dún Òyìnbó di èèwọ ̀ .

(src)="17.10"> Давайте же будем стремиться к миру .
(trg)="16.10"> Ẹ jẹ ́ kí a fẹ ́ àlàáfíà .

(src)="17.11"> Другой пользователь Weibo выразил свою точку зрения в виде рождественского пожелания :
(trg)="16.11"> Òǹlo Weibo mìíràn fi èròńgbàa rẹ ̀ hàn pẹ ̀ lú ohun tí ó fẹ ́ fún Kérésìmesì :

(src)="17.12"> Счастливого Рождества !
(trg)="16.12"> Ẹ kú ọdún Kérésìmesì !

(src)="17.13"> Бог , я люблю тебя !
(trg)="16.13"> Mo nífẹ ̀ ẹ ́ -ẹ ̀ rẹ olúwa !

# ru/2018_10_26_77929_.xml.gz
# yo/2018_12_28_115_.xml.gz


(src)="1.1"> Почему африканские правительства вводят уголовную ответственность за посты в интернете ?
(trg)="1.1"> Kí ló dé tí ìjọba Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ ń f 'òfin de ọ ̀ rọ ̀ sísọ orí-ayélujára ?

(src)="1.2"> Потому что боятся их силы
(trg)="1.2"> Nítorí wọ ́ n bẹ ̀ rù agbára rẹ ̀ .

(src)="1.3"> Студенты университета Харамайя в Эфиопии демонстрируют полуофициальный антиправительственный жест .
(trg)="1.3"> Akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ Ifásitì Haromaya ní Ethiopia ń fi àmì ìtako ìjọba hàn .

(src)="1.4"> Фото широко распространилось в социальных сетях .
(trg)="1.4"> Àwòrán tí a pín lórí ẹ ̀ rọ-alátagbà .

(src)="2.2"> В юридическом и экономическом смысле цена свободы слова быстро растёт по всему континенту .
(trg)="2.2"> Nínú ìlànà òfin àti ọ ̀ rọ ̀ Ajé , iye òmìnira ọ ̀ rọ ̀ ń dìde kárí Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ .

(src)="4.2"> Работники средств массовой информации и граждане были заключены в тюрьму по различным обвинениям , от опубликования « ложной информации » до раскрытия государственных секретов террористам .
(trg)="4.2"> Òṣìṣẹ ́ ìròyìn àti àwọn ọmọ-ìlú ti di èrò àtìmọ ́ lé lórí ẹ ̀ sùn àtẹ ̀ jáde " ìròyìn irọ ́ " títí kan ìkóròyìn ìkòkọ ̀ ìlú sí etí ìgbọ ́ ẹgbẹ ́ afẹ ̀ míṣòfò .

(src)="6.1"> Многие страны имеют своды правил и законы , которые гарантируют право на свободное самовыражение .
(trg)="6.1"> Ọ ̀ pọ ̀ orílẹ ̀ -èdè ló ní àwọn òfin àti àbádòfin tí ó fún ọmọ ènìyàn ní ẹ ̀ tọ ́ sí òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ .

(src)="6.2"> В Нигерии , например , Акт свободы информации даёт гражданам право запрашивать информацию из любого правительственного источника .
(trg)="6.2"> Ní Nàìjíríà , fún àpẹẹrẹ , Àbádòfin Òmìnira Ọ ̀ rọ ̀ fún ọmọ ìlú ní òmìnira láti béèrè fún ìwífun lọ ́ wọ ́ àjọ ìjọba .

(src)="8.2"> Правительства и государственные органы часто используют это как прикрытие для ограничения свободы самовыражения .
(trg)="9.2"> Ìjọba àti àwọn àjọ rẹ ̀ máa ń sábà fi èyí ṣe bójúbójú fún ìtẹríbọlẹ ̀ òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ .

(src)="9.1"> Кто даёт определение слову « оскорбление » ?
(trg)="10.1"> Ta ni ẹni tí ó ń sọ bóyá ọ ̀ rọ ̀ kan jẹ ́ àfojúdi ?

(src)="9.2"> Должны ли официальные лица развивать иммунитет к резким высказываниям ?
(trg)="10.2"> Ǹjẹ ́ ó yẹ kí òṣìṣẹ ́ ìjọba ó ṣe ìmúdàgbà àwọ ̀ -ara tí ó ní ipọn ?

(src)="9.3"> Во многих странах мира граждане имеют право критиковать сотрудников государственных органов .
(trg)="10.3"> Ní àgbáyé , ọmọ-ìlú ní ẹ ̀ tọ ́ láti wá àìṣedéédé aláṣẹ ìjọba .

(src)="10.1"> В 2017 и 2016 годах , нигерийские онлайн-журналисты и блогеры Абубакар Сидик Усман и Кеми Олунлойо оказались в тюрьме на основании Акта о киберпреступлениях по сфабрикованным обвинениям в кибер-преследовании в ходе проведения журналистского расследования .
(trg)="11.1"> Ní ọdún 2017 àti 2016 , oníròyìn orí-ayélujára ọmọ bíbí ìlú Nàìjíríà àti akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Abubakar Sidiq Usman àti Kẹ ́ mi Olúnlọ ́ yọ ̀ ọ ́ tí ta ẹsẹ ̀ àgẹ ̀ rẹ ̀ sí òfin nípasẹ ̀ ṣíṣe iṣẹ ́ ìkóròyìnjọ lóríi Òfin Ẹ ̀ ṣẹ ̀ orí-ayélujára .

(src)="10.2"> Не страдайте в тишине — говорите
(trg)="11.2"> Máà jìyà nínú ìdákẹ ́ rọrọ — máa wí lọ

(src)="10.3"> Само существование этих юридических проблем говорит гражданам , что их голоса имеют значение .
(trg)="11.3"> Ìwà tí ó jẹ ́ gbòògì àwọn ìpèníjà wọ ̀ nyí gẹ ́ gẹ ́ bíi ti òfin ń sọ fún ọmọ-ìlú pé ohùn-un wọn ṣe kókó .

(src)="11.1"> Опыт блогеров Зоны-9 в Эфиопии показывает нам прекрасный тому пример .
(trg)="12.1"> Ìrírí akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 ìlú Ethiopia jẹ ́ àpẹẹrẹ .

(src)="12.3"> Государство заклеймило группу « террористической » за её работу в интернете и заключило её участников в тюрьму почти на 18 месяцев .
(trg)="13.2"> Ìjọba pe ẹgbẹ ́ yìí ni " afẹ ̀ míṣòfò " nítorí àtẹ ̀ jáde orí ẹ ̀ rọ-ayélujára wọn a sì ti wọ ́ n mọ ́ lé fún oṣù 18 .

(src)="13.1"> Члены Зоны-9 Махлет ( слева ) и Зелалем ( справа ) радуются освобождению Бефекаду Хайлу ( второй слева , в шарфе ) в октябре 2015 года .
(trg)="14.1"> Àwọn ọmọ ẹgbẹ ́ Zone9 Mahlet ( òsì ) àti Zelalem ( ọ ̀ tún ) ń dun 'nú fún ìdásílẹ ̀ lẹ ́ wọ ̀ n Befeqadu Hailu ( ẹnìkejì láti ọwọ ́ òsì , pẹ ̀ lú sícáàfù ) ní oṣù kẹwàá ọdún 2015 .

(src)="13.2"> Фотографией поделился Зелалем Кибрет в Twitter .
(trg)="14.2"> Orí Twitter ni Zelalem Kiberet ti pín àwòrán yìí .

(src)="14.2"> Также в нём поучаствовал Джоманекс Касайе , который работал с группой до её ареста ( но сам арестован не был ) .
(trg)="15.2"> Jomanex Kasaye , ẹni tí ó ti bá ẹgbẹ ́ náà ṣiṣẹ ́ kí àtìmọ ́ lé ó tó ṣẹlẹ ̀ ( àmọ ́ tí a kò fi àṣẹ mú ) náà kò gbẹ ́ yìn níbi àpérò .

(src)="15.1"> Несколько членов объединились с Global Voices для написания и перевода статей на амхарский язык .
(trg)="16.1"> Ọ ̀ pọ ̀ lọpọ ̀ nínú ẹgbẹ ́ yìí ti bá Ohùn Àgbáyé ṣe pọ ̀ láti kọ àti ṣe ìtúmọ ̀ ìròyìn sí èdè Amharic .

(src)="16.2"> С четырех сторон света донёсся могучий голос , требующий , чтобы эфиопское правительство освободило блогеров Зоны-9 .
(trg)="17.2"> Láti orígun mẹ ́ rẹ ̀ ẹ ̀ rin àgbáyé , igbe ńlá ni ó gba àwọn akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 sílẹ ̀ lọ ́ wọ ́ ìjọba ilẹ ̀ Ethiopia .

(src)="17.1"> В своих высказываниях на FIFA блогеры отметили , что их присоединение к сообществу Global Voices было ключом к тому , чтобы во время их пребывания в заключении их наконец-то увидели .
(trg)="18.1"> Nínú ọ ̀ rọ ̀ wọn ní FIFA , àwọn akọbúlọ ́ ọ ̀ gù náà sọ wípé ìkẹ ́ gbẹ ́ ẹ wọn nínú Ohùn Àgbáyé ṣe gudugudu méje yàyà mẹ ́ fà ní àsìkò tí àwọn ń fi aṣọ pénpé ro oko ọba .

(src)="17.2"> В выступлении на панельной дискуссии они поблагодарили кампанию , организованную Global Voices , за спасение собственных жизней .
(trg)="18.2"> Ní ètò ìtàkùrọ ̀ sọ wọn , wọ ́ n gbé orí yìn fún ìpolongo Ohùn Àgbáyé tí ó ṣe iṣẹ ́ ribiribi tí ó mú àwọn wà láyé .

(src)="18.1"> Берхайн Тай , модератор дискуссии , попросил участников рассказать об их опыте в тюрьме .
(trg)="19.1"> Berhan Taye , atọ ́ kùn ìtàkùrọ ̀ sọ , bi ẹgbẹ ́ yìí ní ìbéèrè ìrírí wọn ní inú túbú .

(src)="18.2"> По мере того как они говорили , свет на сцене тускнел .
(trg)="19.2"> Bí wọ ́ n ti ṣe sọ , iná amọ ́ roro ìtàgé wálẹ ̀ díẹ ̀ .

(src)="18.3"> Их голоса наполняли комнату тихой силой .
(trg)="19.3"> Ohùn-un wọn mú kí iyàrá ètò pa lọ ́ lọ ́ .

(src)="19.1"> Абел Вабелла — человек , который вёл сайт Global Voices на амхарском языке , оглох на одно ухо из-за пыток , которым подвергся после отказа подписать ложное признание .
(trg)="20.1"> Abel Wabella , alákòóso Ohùn Àgbáyé ní ' Èdè Amharic , kò fi etí ẹ ̀ gbẹ ́ ẹ rẹ ̀ kan gbọ ́ ràn já geere mọ ́ n láti ara ìjìyà oró tí ó jẹ ́ nítorí pé ó kọ ̀ láti ti ọwọ ́ bọ ìwé ìjẹ ́ wọ ́ .

(src)="21.1"> Один из сотрудников службы безопасности , арестовавших Зелалема Кибрета , когда-то был его студентом в университете , где преподавал Зелалем .
(trg)="22.1"> Ọ ̀ kan lára àwọn agbófinró tí ó mú Zelalem Kibret ti fi ìgbà kan rí jẹ ́ akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ Kibret ní Ifásitì tí ó ti ń ṣe iṣẹ ́ olùkọ ́ .

(src)="23.1"> Блогеры Зоны-9 вместе в Аддис-Абебе , 2012 год .
(trg)="24.1"> Àpapọ ̀ Akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 ní Addis Ababa , ní ọdún 2012 .

(src)="23.2"> Слева : Эндалк , Солеяна , Натаель , Абель , Бефекаду , Махлет , Зелалем , Атнаф , Джоманекс .
(trg)="24.2"> Láti ọwọ ́ ọ ̀ tún : Endalk , Soleyana , Natnael , Abel , Befeqadu , Mahlet , Zelalem , Atnaf , Jomanex .

(src)="23.3"> Фото любезно предоставлено Эндалком Чала .
(trg)="24.3"> Endalk Chala ni ó ni àwòrán .

(src)="24.1"> Блогеры Зоны-9 скромно отметили : « Мы не сильные или мужественные ...
(trg)="26.1"> Síbẹ ̀ , akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 ṣe àtúnlò ìfẹ ́ -ìlú-ẹni nínú ọ ̀ rọ ̀ àti ìṣe .

(src)="24.2"> Мы просто рады , что вдохновили других » .
(trg)="26.2"> Ó gba ìgboyà láti fẹ ́ ràn ìlú ẹni pàápàá lẹ ́ yìn ìjìyà nítorí wípé a sọ ̀ rọ ̀ síta .

(src)="25.1"> Однако они придали новое значение слову « патриотизм » своими словами и поступками .
(trg)="27.2"> Níwọ ̀ n ìgbà tí òde ti já ọgbọ ́ n àtamátàsè , ẹyẹ Eneke náà ti kọ ́ fífò láì bà .