# pt/2018_12_14_pela-primeira-vez-voo-e-tripulado-somente-por-mulheres-em-mocambique_.xml.gz
# yo/2018_12_23_103_.xml.gz


(src)="1.1"> Pela primeira vez , vôo é tripulado somente por mulheres em Moçambique
(trg)="1.1"> Òṣìṣẹ ́ inú ọkọ ̀ òfuurufú olóbìrin nìkan wọ ìwé ìtàn ní Mozambique

(src)="3.1"> De facto , pela primeira vez na história da aviação civil do país , um avião foi triuplado somente por mulheres .
(trg)="1.2"> Ikọ ̀ awakọ ̀ òfuurufú olóbìrin àkọ ́ kọ ́ irúu rẹ ̀ ní Mozambique | A lo àwòrán pẹ ̀ lú àṣẹ láti ọwọ ́ Meck Antonio .

(src)="5.1"> Ambas fazem parte de uma companhia aérea denominada MEX , criada em Setembro de 1995 como Departamento de Operações Especiais da LAM — Linhas Aéreas de Moçambique .
(trg)="2.1"> Ọjọ ́ ìtàn ni ọjọ ́ yìí : ojú yìí ni ogunlọ ́ gọ ̀ ọmọ-ìlú Mozambique fi wo ìṣẹ ̀ lẹ ̀ ọjọ ́ 14 , oṣù Ọ ̀ pẹ ọdún 2018 nígbà tí , fún ìgbà àkókọ ́ nínú ìtàn ìgbésí ayé ètò ọkọ ̀ òfuurufú ìlú náà , tí obìnrin jẹ ́ atukọ ̀ .

(src)="5.2"> Começou as operações e tornou-se o Moçambique Expresso em 1995 como companhia aérea independente .
(trg)="4.1"> Àwọn obìrin wọ ̀ nyí wà nínú ẹgbẹ ́ MEX , ilé-iṣẹ ́ tí a dá sílẹ ̀ gẹ ́ gẹ ́ bíi Ẹ ̀ ka Iṣẹ ́ Àkànṣe LAM — Linhas Aéreas de Moçambique .

(src)="7.1"> UM DIA NA HISTÓRIA- Vôo totalmente tripulado por mulheres
(trg)="4.2"> Ní 1995 , ó bẹ ̀ rẹ ̀ iṣẹ ́ bíi ilé-iṣẹ ́ ọkọ ̀ òfuurufú aládàáni , Mozambique Express .

(src)="8.1"> Vôo TM112 / 3 MPM- VPY- MPM ( Maputo- Chimoio- Maputo )
(trg)="5.2"> ỌJỌ ́ ÌTÀN - Ikọ ̀ ọkọ ̀ òfuurufú TM112 / 3 MPM-VPY-MPM ( Maputo-Chimoio-Maputo )

(src)="9.1"> Parabéns MEX !
(trg)="6.1"> MEX kú oríire !

(src)="10.1"> Parabéns tripulação !
(trg)="7.1"> Ikọ ̀ ẹ kú oríire !

(src)="11.1"> Parabéns Moçambique !
(trg)="8.1"> Mozambique , kú oríire !

(src)="11.2"> Por mais mulheres em todos os sectores .
(trg)="8.2"> Fún ọ ̀ pọ ̀ lọpọ ̀ obìrin nínú iṣẹ ́ gbogbo .

(src)="11.8"> Por exemplo , na África do Sul o facto teve lugar este ano , enquanto que na Etiópia sucedeu em 2017 .
(trg)="9.2"> Awọn atukọ ̀ títí kan òṣìṣẹ ́ gbogbo , ọkọ ̀ òfuurufú láti Addis Ababa ní Ethiopia sí Èkó ní Nàìjíríà — jẹ ́ obìrin pátápátá porongodo .

# pt/2018_11_06_por-que-os-governos-africanos-estao-criminalizando-a-liberdade-de-expressao-on-line-porque-temem-seu-poder_.xml.gz
# yo/2018_12_28_115_.xml.gz


(src)="1.1"> Por que os governos africanos estão criminalizando a liberdade de expressão on-line ?
(trg)="1.1"> Kí ló dé tí ìjọba Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ ń f 'òfin de ọ ̀ rọ ̀ sísọ orí-ayélujára ?

(src)="1.2"> Porque temem seu poder
(trg)="1.2"> Nítorí wọ ́ n bẹ ̀ rù agbára rẹ ̀ .

(src)="1.4"> Foto compartilhada amplamente nas redes sociais .
(trg)="1.4"> Àwòrán tí a pín lórí ẹ ̀ rọ-alátagbà .

(src)="2.2"> Em termos legais e econômicos , o custo de se manifestar está aumentando rapidamente em todo o continente .
(trg)="2.2"> Nínú ìlànà òfin àti ọ ̀ rọ ̀ Ajé , iye òmìnira ọ ̀ rọ ̀ ń dìde kárí Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ .

(src)="3.1"> Enquanto a maioria dos governos são considerados democráticos pois realizam eleições com candidatos multipartidários e professam ideais de participação , na prática , muitos estão mais próximos da ditadura - e parecem exercer mais controle sobre o espaço digital a cada dia que passa .
(trg)="3.1"> Nígbà tí àwọn ìjọba kan mọ rírì ètò ìjọba àwa-arawa nípasẹ ̀ ṣíṣe ìbò pẹ ̀ lú ọlọ ́ pọ ̀ -ẹgbẹ ́ òṣèlú àti sọ nígbangba nípa àjọṣe , nínú ìṣe , ọ ̀ pọ ̀ máa ń lo àṣẹ tí ò ṣe é yí padà — wọ ́ n sì ń lo agbára àṣẹ yìí lórí ẹ ̀ rọ-ayárabíàṣá bí ọjọ ́ ṣe ń gun orí ọjọ ́ .

(src)="4.1"> Camarões , Tanzânia , Uganda , Etiópia , Nigéria , e Benim testemunharam recentes paralisações na internet , imposição de impostos sobre o uso de blogues e redes sociais , e a prisão de jornalistas .
(trg)="4.1"> Cameroon , Tanzania , Uganda , Ethiopia , Nigeria , àti Benin ti ní Ìtìpa Ẹ ̀ rọ-ayélujára , ìjọba ti fi owó-orí lé lílo búlọ ́ ọ ̀ gù àti ẹ ̀ rọ-alátagbà , wọ ́ n sì ti fi ọwọ ́ ṣìgún òfin mú oníròyìn .

(src)="4.2"> Funcionários dos meios de comunicação e cidadãos foram presos sob acusações que variam desde a publicação de “ informações falsas ” até a revelação de segredos de Estado ao terrorismo .
(trg)="4.2"> Òṣìṣẹ ́ ìròyìn àti àwọn ọmọ-ìlú ti di èrò àtìmọ ́ lé lórí ẹ ̀ sùn àtẹ ̀ jáde " ìròyìn irọ ́ " títí kan ìkóròyìn ìkòkọ ̀ ìlú sí etí ìgbọ ́ ẹgbẹ ́ afẹ ̀ míṣòfò .

(src)="5.1"> No recente Fórum sobre a Liberdade na Internet na África ( FIFA , na sigla em inglês ) , realizado em Acra , Gana , um grupo de palestrantes de vários países africanos disseram ter medo que os governos daquele continente estivessem interessados em controlar o espaço digital para manter os cidadãos sob controle .
(trg)="5.1"> Ní ibi Àpérò Òmìnira Ẹ ̀ rọ-ayélujára ní Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ ( FIFA ) tí ó wáyé ní Accra , Ghana , ikọ ̀ akópa láti àwọn ìlú ilẹ ̀ Adúláwọ ̀ pátá sọ wípé kò ní ṣe ẹnu rere bí ìjọba bá fi òfin de ọmọ-ìlú tí ó ń lo ẹ ̀ rọ-ayárabíaṣá .

(src)="6.2"> Na Nigéria , por exemplo , a Lei de Liberdade de Informação concede aos cidadãos o direito de exigir informações de qualquer órgão do governo .
(trg)="6.3"> Abala 22 ìwé òfin ọdún 1999 pèsè fún ẹ ̀ tọ ́ òmìnira ìròyìn àti Abala 39 fi lélẹ ̀ wípé " gbogbo ènìyàn ni ó ní ẹ ̀ tọ ́ sí òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ , títí kan òmìnira láti gbá ìròyìn mú àti gba ọgbọ ́ n àti ìwífun láì sí ìdíwọ ́ ... "

(src)="7.1"> No entanto , a Nigéria promulgou outras leis que as autoridades usam para negar esses direitos acima mencionados .
(trg)="7.1"> Síbẹ ̀ , Nàìjíríà tí tẹ àwọn òfin kan tí ó tẹ orí àwọn ẹ ̀ tọ ́ òkè yìí bọlẹ ̀ .

(src)="9.1"> É preocupante a criação de leis com termos ambíguos e subjetivos como " inconveniência " ou " insulto " .
(trg)="9.1"> Ìṣòfin àìdájú àti àwọn gbólóhùn bíi " ìnira " tàbí " ìwọ ̀ sí " jẹ ́ nǹkan tí a ní láti mójútó .

(src)="9.2"> Os governos e seus agentes costumam usar isso como um modo de suprimir a liberdade de expressão .
(trg)="9.2"> Ìjọba àti àwọn àjọ rẹ ̀ máa ń sábà fi èyí ṣe bójúbójú fún ìtẹríbọlẹ ̀ òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ .

(src)="10.1"> Quem determina a definição de um insulto ?
(trg)="10.1"> Ta ni ẹni tí ó ń sọ bóyá ọ ̀ rọ ̀ kan jẹ ́ àfojúdi ?

(src)="10.2"> Os funcionários públicos devem desenvolver a resistência necessária ?
(trg)="10.2"> Ǹjẹ ́ ó yẹ kí òṣìṣẹ ́ ìjọba ó ṣe ìmúdàgbà àwọ ̀ -ara tí ó ní ipọn ?

(src)="10.4"> Por que os africanos não têm este direito como parte essencial da liberdade de expressão ?
(trg)="10.4"> Kí ló dé tí Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ kò ní ẹ ̀ tọ ́ láti ṣẹ ̀ gẹ ́ gẹ ́ bí ẹ ̀ ka tí ó ṣe pàtàkì nínú òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ ?

(src)="11.1"> Em 2016 e 2017 , os jornalistas e blogueiros nigerianos Abubakar Sidiq Usman e Kemi Olunloyo foram falsamente acusados de perseguições on-line ( cyberstalking ) em conexão com investigações jornalísticas , com base na Lei de Cibercrime .
(trg)="11.1"> Ní ọdún 2017 àti 2016 , oníròyìn orí-ayélujára ọmọ bíbí ìlú Nàìjíríà àti akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Abubakar Sidiq Usman àti Kẹ ́ mi Olúnlọ ́ yọ ̀ ọ ́ tí ta ẹsẹ ̀ àgẹ ̀ rẹ ̀ sí òfin nípasẹ ̀ ṣíṣe iṣẹ ́ ìkóròyìnjọ lóríi Òfin Ẹ ̀ ṣẹ ̀ orí-ayélujára .

(src)="11.2"> Não sofra em silêncio - continue falando
(trg)="11.2"> Máà jìyà nínú ìdákẹ ́ rọrọ — máa wí lọ

(src)="11.3"> A própria existência desses desafios legais diz aos cidadãos que suas vozes importam .
(trg)="11.3"> Ìwà tí ó jẹ ́ gbòògì àwọn ìpèníjà wọ ̀ nyí gẹ ́ gẹ ́ bíi ti òfin ń sọ fún ọmọ-ìlú pé ohùn-un wọn ṣe kókó .

(src)="11.4"> Desde a proibição na Tanzânia de espalhar informações on-line falsas , imprecisas e ilusórias até o imposto sobre as redes sociais em Uganda , que visa conter “ boatos ” , o tumulto produzido nas plataformas digitais assusta regimes opressivos .
(trg)="11.4"> Kí a mú un láti Ìdádúró Tanzania tí ó dá lóríi ìtànká " ìròyìn irọ ́ , ìtànjẹ , tàbí ìròyìn tí ò pé ojú òṣùwọ ̀ n " lórí ayélujára títí kan owó-orí Uganda fún ìlò ẹ ̀ rọ-alátagbà fún ìgbógunti " àhesọ " , ariwo orí ẹ ̀ rọ-ayárabíaṣá ń já àwọn ìjọba aninilára láyà .

(src)="11.5"> Em alguns casos , pode até levá-los a rescindir suas ações .
(trg)="11.5"> Ní ìgbà mìíràn , ó máa mú wọn pa àwọn ìwàa wọn tì .

(src)="12.1"> A experiência dos blogueiros Zone9 da Etiópia é um evidente exemplo disso .
(trg)="12.1"> Ìrírí akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 ìlú Ethiopia jẹ ́ àpẹẹrẹ .

(src)="13.1"> Em 2014 , nove escritores etíopes foram presos e torturados por causa de um projeto de blogue coletivo no qual escreveram sobre violações de direitos humanos feitas pelo governo anterior da Etiópia , ousando a enfretar o poder com a verdade .
(trg)="13.1"> Ní ọdún 2014 , àwọn òǹkọ ̀ wé ọmọ bíbí Ethiopia mẹ ́ sàn-án lọ sí ẹ ̀ wọ ̀ n àti jìyà oró látàrí iṣẹ ́ àjọṣepọ ̀ tí wọ ́ n jọ kọ nípa ìtẹsẹ ̀ àgẹ ̀ rẹ ̀ sí ẹ ̀ tọ ́ ọmọ-ènìyàn ìjọba àná ìlú Ethiopia , kí òótọ ́ ó di mímọ ̀ .

(src)="13.2"> O Estado os classifcou como " terroristas " por sua atividade on-line e eles ficaram detidos por quase 18 meses .
(trg)="13.2"> Ìjọba pe ẹgbẹ ́ yìí ni " afẹ ̀ míṣòfò " nítorí àtẹ ̀ jáde orí ẹ ̀ rọ-ayélujára wọn a sì ti wọ ́ n mọ ́ lé fún oṣù 18 .

(src)="14.1"> Os membros da Zone9 , Mahlet ( à esquerda ) e Zelalem ( à direita ) , regozijaram-se com a libertação de Befeqadu Hailu ( segundo à esquerda , com cachecol ) em outubro de 2015 .
(trg)="14.1"> Àwọn ọmọ ẹgbẹ ́ Zone9 Mahlet ( òsì ) àti Zelalem ( ọ ̀ tún ) ń dun 'nú fún ìdásílẹ ̀ lẹ ́ wọ ̀ n Befeqadu Hailu ( ẹnìkejì láti ọwọ ́ òsì , pẹ ̀ lú sícáàfù ) ní oṣù kẹwàá ọdún 2015 .

(src)="14.2"> Foto compartilhada no Twitter por Zelalem Kiberet .
(trg)="14.2"> Orí Twitter ni Zelalem Kiberet ti pín àwòrán yìí .

(src)="15.1"> Seis membros do grupo agora liberado tiveram sua primeira aparição internacional em Gana , durante a conferência da FIFA : Atnaf Berhane , Befeqadu Hailu Techane , Zelalem Kibret , Natnael Feleke Aberra e Abel Wabella estiveram presentes .
(trg)="15.1"> Àwọn mẹ ́ fà lára àwọn ẹgbẹ ́ náà tí ó ti gba òmìnira báyìí ṣe ìtàkùrọ ̀ sọ àgbáyé àkọ ́ kọ ́ ní ìlú Ghana ní àsìkò àpérò FIFA : Atnaf Berhane , Befeqadu Hailu Techane , Zelalem Kibret , Natnael Feleke Aberra , àti Abel Wabella náà wá sí àpérò .

(src)="16.1"> Vários membros colaboraram com a Global Voices como autores e tradutores em amárico .
(trg)="16.1"> Ọ ̀ pọ ̀ lọpọ ̀ nínú ẹgbẹ ́ yìí ti bá Ohùn Àgbáyé ṣe pọ ̀ láti kọ àti ṣe ìtúmọ ̀ ìròyìn sí èdè Amharic .

(src)="16.2"> Como membros da comunidade , a Global Voices fez campanha e mobilizou a comunidade global de direitos humanos para protestar sobre o caso desde a primeira noite em que foram presos .
(trg)="16.2"> Gẹ ́ gẹ ́ bí ọmọ ẹgbẹ ́ Ohùn Àgbáyé ṣe ìpolongo àti ìpanupọ ̀ ajàfúnẹ ̀ tọ ́ ọmọnìyàn àgbáyé gẹ ́ gẹ ́ bi agbẹnusọ láti ọjọ ́ tí wọ ́ n dé akoto ọba .

(src)="17.2"> Dos quatro cantos do mundo , surgiu um poderoso clamor exigindo que o governo etíope libertasse os blogueiros da Zone9 .
(trg)="17.2"> Láti orígun mẹ ́ rẹ ̀ ẹ ̀ rin àgbáyé , igbe ńlá ni ó gba àwọn akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 sílẹ ̀ lọ ́ wọ ́ ìjọba ilẹ ̀ Ethiopia .

(src)="18.1"> Em seus comentários na FIFA , os blogueiros disseram que a afiliação deles na comunidade da Global Voices foi decisiva para dar-lhes visibilidade durante o período de prisão .
(trg)="18.1"> Nínú ọ ̀ rọ ̀ wọn ní FIFA , àwọn akọbúlọ ́ ọ ̀ gù náà sọ wípé ìkẹ ́ gbẹ ́ ẹ wọn nínú Ohùn Àgbáyé ṣe gudugudu méje yàyà mẹ ́ fà ní àsìkò tí àwọn ń fi aṣọ pénpé ro oko ọba .

(src)="19.1"> Berhan Taye , o moderador do painel , pediu ao grupo para recontar suas experiências na prisão .
(trg)="19.1"> Berhan Taye , atọ ́ kùn ìtàkùrọ ̀ sọ , bi ẹgbẹ ́ yìí ní ìbéèrè ìrírí wọn ní inú túbú .

(src)="19.2"> Enquanto falavam , as luzes do palco diminuíram .
(trg)="19.2"> Bí wọ ́ n ti ṣe sọ , iná amọ ́ roro ìtàgé wálẹ ̀ díẹ ̀ .

(src)="19.3"> Suas vozes encheram a sala com um poder silencioso .
(trg)="19.3"> Ohùn-un wọn mú kí iyàrá ètò pa lọ ́ lọ ́ .

(src)="20.1"> Abel Wabella , que dirigiu o site da Global Voices em amárico , perdeu a audição em um ouvido devido à tortura que sofreu depois de se recusar a assinar uma falsa confissão .
(trg)="20.1"> Abel Wabella , alákòóso Ohùn Àgbáyé ní ' Èdè Amharic , kò fi etí ẹ ̀ gbẹ ́ ẹ rẹ ̀ kan gbọ ́ ràn já geere mọ ́ n láti ara ìjìyà oró tí ó jẹ ́ nítorí pé ó kọ ̀ láti ti ọwọ ́ bọ ìwé ìjẹ ́ wọ ́ .

(src)="24.1"> Blogueiros da Zone9 juntos em Adis Abeba , em 2012 .
(trg)="24.1"> Àpapọ ̀ Akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 ní Addis Ababa , ní ọdún 2012 .

(src)="24.2"> Da esquerda : Endalk , Soleyana , Natnael , Abel , Befeqadu , Mahlet , Zelalem , Atnaf , Jomanex .
(trg)="24.2"> Láti ọwọ ́ ọ ̀ tún : Endalk , Soleyana , Natnael , Abel , Befeqadu , Mahlet , Zelalem , Atnaf , Jomanex .

(src)="24.3"> Foto cedida por Endalk Chala
(trg)="24.3"> Endalk Chala ni ó ni àwòrán .

(src)="25.1"> Com modéstia , os blogueiros da Zone9 disseram : “ Nós não somos pessoas fortes ou corajosas … estamos apenas felizes por inspirar os outros ” .
(trg)="25.1"> Pẹ ̀ lú ìrẹ ̀ lẹ ̀ , àwọn akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 sọ wípé : " A kò kí ń ṣe ẹni tí ó ní okun tàbí ìgboyà .. inúu wa dùn nítorí wípé a fún àwọn ènìyàn mìíràn ní ìmísí ni . "

(src)="26.1"> No entanto , os blogueiros redefiniram o patriotismo com suas palavras e ações .
(trg)="26.1"> Síbẹ ̀ , akọbúlọ ́ ọ ̀ gù Zone9 ṣe àtúnlò ìfẹ ́ -ìlú-ẹni nínú ọ ̀ rọ ̀ àti ìṣe .

(src)="26.2"> É preciso muita coragem para amar o próprio país após ter sofrido nas mãos dele por se manifestar .
(trg)="26.2"> Ó gba ìgboyà láti fẹ ́ ràn ìlú ẹni pàápàá lẹ ́ yìn ìjìyà nítorí wípé a sọ ̀ rọ ̀ síta .

(src)="27.1"> O jornalista ugandês Charles Onyango-Obbo , também presente na FIFA , compartilhou um provérbio igbo popularizado pelo escritor nigeriano Chinua Achebe , que diz :
(trg)="27.1"> Oníròyìn ọmọ Uganda Charles Onyango-Obbo , tí òun náà wà ní FIFA , mẹ ́ nu ba òwe Igbo tí gbajúgbajà òǹkọ ̀ wée nì Chinua Achebe mú di mímọ ́ tí ó sọ wípé :

(src)="27.3"> Em essência , ele quis dizer que , para manter os espaços digitais livres e seguros , os envolvidos nessa luta devem criar novos métodos .
(trg)="27.3"> Ní àkótán , ohun tí ó fẹ ́ sọ ní wípé láti mú ayélujára wà ní ipò ọ ̀ fẹ ́ àti ààbò , àwọn tí ó ń jà fún èyí nílò láti wá ọgbọ ́ n mìíràn dá .