# mg/2018_12_16_132001_.xml.gz
# yo/2018_12_23_103_.xml.gz
(src)="1.1"> Andiam-panamory tsy misy afa-tsy vehivavy , manoratra ny tantara ao Mozambika
(trg)="1.1"> Òṣìṣẹ ́ inú ọkọ ̀ òfuurufú olóbìrin nìkan wọ ìwé ìtàn ní Mozambique
(src)="4.1"> Vehivavy mpikambana ao amin 'ny MEX avokoa ry zareo , sampan-draharaha iray noforonina tany aloha ary nomena ny anarana hoe Departemanta Misahana Raharaha Manokana tao amin 'ny LAM — Linhas Aéreas de Moçambique .
(trg)="4.1"> Àwọn obìrin wọ ̀ nyí wà nínú ẹgbẹ ́ MEX , ilé-iṣẹ ́ tí a dá sílẹ ̀ gẹ ́ gẹ ́ bíi Ẹ ̀ ka Iṣẹ ́ Àkànṣe LAM — Linhas Aéreas de Moçambique .
(src)="4.2"> Tamin 'ny 1995 , nanomboka ny asany toy ny orinasam-pitaterana tsy miankina izy io , ny Mozambique Express .
(trg)="4.2"> Ní 1995 , ó bẹ ̀ rẹ ̀ iṣẹ ́ bíi ilé-iṣẹ ́ ọkọ ̀ òfuurufú aládàáni , Mozambique Express .
(src)="5.1"> Nisy sata fiarahabana nipetraka tao amin 'ny Facebook , nalefan 'ny feminista iray mpikatroka , Eliana Nzualo , nahazo fanehoankevitra manodidina ny 450 hatreto , naverina nozaraina in-460 mahery , ary nahangona fomba fijery efa ho 2.000 :
(trg)="5.1"> Àtẹ ̀ jáde ìkíni orí Facebook láti ọwọ ́ ajàfúnẹ ̀ tọ ́ obìrin Eliana Nzualo , ti ní ìsọsí tí ó tó 450 , tí a ti pín tó ìgbà 460 , àti pé ọ ̀ pọ ̀ èsì tí ó tó 2,000 ni ó gbà :
(src)="7.1"> Arahabaina ny MEX !
(trg)="6.1"> MEX kú oríire !
(src)="8.1"> Arahabanina ny tarika !
(trg)="7.1"> Ikọ ̀ ẹ kú oríire !
(src)="9.1"> Arahabaina i Mozambika !
(trg)="8.1"> Mozambique , kú oríire !
(src)="9.2"> Mba ho betsaka hatrany anie ireo vehivavy any anatin 'ny sehatra rehetra any .
(trg)="8.2"> Fún ọ ̀ pọ ̀ lọpọ ̀ obìrin nínú iṣẹ ́ gbogbo .
(src)="9.4"> Vitsivitsy ny vehivavy ao anatin 'ny resaka fifamoivoizana an-habakabaka , tena vitsy , tsy eto ihany io fa manerana ny tany mihitsy .
(trg)="8.4"> Obìrin kò pọ ̀ nínú iṣẹ ́ ọkọ ̀ òfuurufú , bẹ ́ ẹ ̀ ni ó sì ṣe rí káríayé .
(src)="9.5"> Heveriko fa tokony hahatsapa rehareha ireo vehivavy izay nihevitra fa natokana ho an 'ny lehilahy fotsiny io asa io .
(trg)="8.5"> Mo rò ó wípé àwọn obìrin tí ó ronú láti ṣe iṣẹ ́ tí ọkùnrin máa ń ṣe , gbọdọ ̀ gbéraga .
(src)="9.6"> Tsy maningana i Mozambika .
(trg)="8.6"> Mozambique nìkan kọ ́ .
(src)="9.7"> Tamin 'ny Aogositra 2018 , sambany ho an 'ny asa tao amin 'ny SAA , misahana sidina iraisampirenena , no nahitàna tarika tsy misy afa-tsy vehivavy nandray ny habakabaka hitatitra mpandeha avy ao Johannesburg ho any Sao Paulo , Brezila
(trg)="8.7"> Ní oṣù Ògún ọdún 2018 , nínú ọkọ ̀ òfuurufú ìlú apá Gúúsù Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ SAA , ìrìnàjò ìlú dé ìlú pẹ ̀ lú ikọ ̀ olóbìrin fò ní ojú sánmà wọ ́ n sì kó èrò láti Johannesburg sí Sao Paulo , Brazil .