# en/2018_12_15_an-all-female-flight-crew-makes-history-in-mozambique_.xml.gz
# yo/2018_12_23_103_.xml.gz
(src)="1.1"> An all-female flight crew makes history in Mozambique · Global Voices
(trg)="1.1"> Òṣìṣẹ ́ inú ọkọ ̀ òfuurufú olóbìrin nìkan wọ ìwé ìtàn ní Mozambique
(src)="1.2"> Mozambique 's first all-female crew | Photo used with permission from Meck Antonio .
(trg)="1.2"> Ikọ ̀ awakọ ̀ òfuurufú olóbìrin àkọ ́ kọ ́ irúu rẹ ̀ ní Mozambique | A lo àwòrán pẹ ̀ lú àṣẹ láti ọwọ ́ Meck Antonio .
(src)="2.1"> It is a historic day : that is how many Mozambicans regard December 14 , 2018 when , for the first time in the country 's civil aviation history , an airplane was operated solely by women .
(trg)="2.1"> Ọjọ ́ ìtàn ni ọjọ ́ yìí : ojú yìí ni ogunlọ ́ gọ ̀ ọmọ-ìlú Mozambique fi wo ìṣẹ ̀ lẹ ̀ ọjọ ́ 14 , oṣù Ọ ̀ pẹ ọdún 2018 nígbà tí , fún ìgbà àkókọ ́ nínú ìtàn ìgbésí ayé ètò ọkọ ̀ òfuurufú ìlú náà , tí obìnrin jẹ ́ atukọ ̀ .
(src)="4.1"> The women are members of MEX , an entity originally created as the Special Operations Department of LAM — Linhas Aéreas de Moçambique .
(trg)="4.1"> Àwọn obìrin wọ ̀ nyí wà nínú ẹgbẹ ́ MEX , ilé-iṣẹ ́ tí a dá sílẹ ̀ gẹ ́ gẹ ́ bíi Ẹ ̀ ka Iṣẹ ́ Àkànṣe LAM — Linhas Aéreas de Moçambique .
(src)="4.2"> In 1995 , it began operations as an independent airline , Mozambique Express .
(trg)="4.2"> Ní 1995 , ó bẹ ̀ rẹ ̀ iṣẹ ́ bíi ilé-iṣẹ ́ ọkọ ̀ òfuurufú aládàáni , Mozambique Express .
(src)="5.1"> A congratulatory Facebook status update posted by feminist activist Eliana Nzualo , has so far attracted nearly 450 comments , been shared more than 460 times , and garnered close to 2,000 reactions :
(trg)="5.1"> Àtẹ ̀ jáde ìkíni orí Facebook láti ọwọ ́ ajàfúnẹ ̀ tọ ́ obìrin Eliana Nzualo , ti ní ìsọsí tí ó tó 450 , tí a ti pín tó ìgbà 460 , àti pé ọ ̀ pọ ̀ èsì tí ó tó 2,000 ni ó gbà :
(src)="5.2"> A HISTORIC DAY - All-female crew
(trg)="5.2"> ỌJỌ ́ ÌTÀN - Ikọ ̀ ọkọ ̀ òfuurufú TM112 / 3 MPM-VPY-MPM ( Maputo-Chimoio-Maputo )
(src)="7.1"> Congratulations MEX !
(trg)="6.1"> MEX kú oríire !
(src)="8.1"> Congratulations crew !
(trg)="7.1"> Ikọ ̀ ẹ kú oríire !
(src)="9.1"> Congratulations , Mozambique !
(trg)="8.1"> Mozambique , kú oríire !
(src)="9.2"> For more women in all sectors .
(trg)="8.2"> Fún ọ ̀ pọ ̀ lọpọ ̀ obìrin nínú iṣẹ ́ gbogbo .
(src)="9.3"> Social activist Mauro Brito added that women should be proud " when are represented in various sectors " :
(trg)="8.3"> Àjàfúnẹ ̀ tọ ́ ìkẹ ́ gbẹ ́ Mauro Brito sọ ní tirẹ ̀ wípé obìrin gbọ ́ dọ ̀ ní ìgbéraga " nígbàtí bá jẹ ́ aṣojú nínú iṣẹ ́ gbogbo " :
(src)="9.4"> In aviation there are few women , very few , this is not only here but in the whole world .
(trg)="8.4"> Obìrin kò pọ ̀ nínú iṣẹ ́ ọkọ ̀ òfuurufú , bẹ ́ ẹ ̀ ni ó sì ṣe rí káríayé .
(src)="9.5"> I imagine the women who thought this profession was for men only , should feel proud .
(trg)="8.5"> Mo rò ó wípé àwọn obìrin tí ó ronú láti ṣe iṣẹ ́ tí ọkùnrin máa ń ṣe , gbọdọ ̀ gbéraga .
(src)="9.6"> Mozambique is not alone .
(trg)="8.6"> Mozambique nìkan kọ ́ .
(src)="10.1"> Eight months earlier , in December 2017 , Ethiopian Airlines operated its first ever flight staffed by an all-female crew .
(trg)="8.7"> Ní oṣù Ògún ọdún 2018 , nínú ọkọ ̀ òfuurufú ìlú apá Gúúsù Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ SAA , ìrìnàjò ìlú dé ìlú pẹ ̀ lú ikọ ̀ olóbìrin fò ní ojú sánmà wọ ́ n sì kó èrò láti Johannesburg sí Sao Paulo , Brazil .
(src)="10.2"> From pilots to cabin crew , check-in staff to flight dispatchers , the flight — from Addis Ababa in Ethiopia to Lagos in Nigeria — was ( wo ) manned entirely by women .
(trg)="9.1"> Oṣù méjìlá sẹ ́ yìn , ní oṣù Ọ ̀ pẹ ọdún 2017 , Ilé-iṣẹ ́ Ọkọ ̀ òfuurufú Ethiopia fún ìgbà àkókọ ́ gbé ikọ ̀ òṣìṣẹ ́ bìrin fò .
(trg)="9.2"> Awọn atukọ ̀ títí kan òṣìṣẹ ́ gbogbo , ọkọ ̀ òfuurufú láti Addis Ababa ní Ethiopia sí Èkó ní Nàìjíríà — jẹ ́ obìrin pátápátá porongodo .
# en/2018_12_22_chinas-campaign-against-western-festivals-makes-celebrating-a-difficult-choice-for-citizens_.xml.gz
# yo/2018_12_23_99_.xml.gz
(src)="1.1"> China 's campaign against Christmas makes celebrating a difficult choice for citizens · Global Voices
(trg)="1.1"> Ìpolongo ìtakò Kérésìmesì ìlú China mú yíyan àjọyọ ̀ le fún ọmọ-ìlú
(src)="1.2"> Written on the classroom boards : " Act and reject Western festival " and " Promote traditional culture , reject Western festival " .
(trg)="1.2"> Ohun tí a kọ sí ojú pátákó : " Gbé Ìgbésẹ ̀ kí o sì kọ àjọ ̀ dún Òyìnbó " àti " Ṣe ìgbélárugẹ àṣà ìbílẹ ̀ , kọ àjọ ̀ dún Òyìnbó " .
(src)="1.3"> Images from Weibo .
(trg)="1.3"> Àwòrán láti Weibo .
(src)="2.1"> Christmas is approaching but instead of feeling joyful , many in mainland China have expressed frustration over China 's ideological campaign against Christmas as a Western festival .
(trg)="2.1"> Kérésìmesì ń sún mọ ́ dẹ ̀ dẹ ̀ ṣùgbọ ́ n kàkà kí inú àwọn tí ó ń gbé ní orí-ilẹ ̀ ìlú China ò dùn , ọ ̀ pọ ́ ti fi ẹ ̀ hónú-u wọn hàn lórí ìpolongo tí ó tako ayẹyẹ Kérésìmesì tí ó kà á sí àjọ ̀ dún Òyìnbó .
(src)="3.1"> In 2017 , the Communist Party of China 's central committee and state council issued an official document entitled “ Suggestions on the implementation of projects to promote and develop traditional Chinese culture excellence ” .
(trg)="3.1"> Ní ọdún 2017 , ìgbìmọ ̀ àgbà àti àjọ ìpínlẹ ̀ lábẹ ́ ẹgbẹ ́ olóṣèlú Communist ìlú China kọ ìwé àṣẹ kan tí a pe àkọlée rẹ ̀ ní " Ìmọ ̀ ràn lórí imúdiṣíṣẹ iṣẹ ́ ìgbélárugẹ àti ìdàgbà àṣà ìbílẹ ̀ China dé ibi gíga " .
(src)="3.2"> They outlined a cultural revival project that lists Chinese festivals like the Lunar New Year and the Lantern Festival , among others , as cultural conventions worthy of celebration .
(trg)="3.2"> Wọ ́ n la àwọn àkànṣe iṣẹ ́ ìsọjí àṣà bíi Ọdún Òṣùpá Tuntun àti Àjọ ̀ dún Àtùpà sílẹ ̀ , láì pa ìyìókù tì , gẹ ́ gẹ ́ bí ìpàgọ ́ tí ó jẹ mọ ́ ti àṣà tí ó lákaakì .
(src)="4.1"> To implement this policy , Chinese authorities have launched a series of ideological campaigns to crack down on non-Chinese celebrations .
(trg)="4.1"> Kí òfin yìí lè di àmúṣẹ , ìjọba China ti ṣe ìfilọ ́ lẹ ̀ àwọn ètò ìpolongo kéékèèké mélòó kan fún ìkọ ̀ yìn sí àwọn ayẹyẹ tí kì í ṣe ti ìbílẹ ̀ China .
(src)="4.2"> This year , just before Christmas , authorities in some cities such as Langfang , in Hebei province , have demanded shops to remove Christmas decorations on the streets and in window displays .
(trg)="4.2"> Ọdún nìín , ọjọ ́ díẹ ̀ sí Kérésìmesì , ìjọba ní àwọn ìlú ńlá bíi Langfang , ní agbègbèe Hebei , ti pa á ní àṣẹ fún ìsọ ̀ gbogbo láti yọ ẹ ̀ ṣọ ́ ọdún Kérésìmesì kúrò lójú títí àti fèrèsé .
(src)="5.1"> Anti-Western festival commentaries have flooded Chinese social media , making Christmas celebrations a difficult choice for some who feel they must keep their joy a secret .
(trg)="5.1"> Ọ ̀ rọ ̀ àlùfànṣá tí ó dá lórí ìtako àjọ ̀ dún Òyìnbó ti gba ẹ ̀ rọ-alátagbà ìlú China kan , èyí mú kí yíyan ayẹyẹ Kérésìmesì láàyò le koko fún àwọn tí ó rò wípé ní ìkọ ̀ kọ ̀ ni ayọ ̀ àwọn gbọdọ ̀ wà .
(src)="6.1"> Screen capture of news feed on anti-western festival commentaries on Weibo .
(trg)="7.1"> Ònlo Weibo Long Zhigao ya àwòrán ìròyìn orí WeChat ti rẹ ̀ ní orí Weibo ní ìfihàn àríyànjiyàn .
(src)="7.2"> The headlines on the feed are 1 .
(trg)="7.2"> Kókó ìròyìn àkọ ́ kọ ́ 1 .
(src)="7.3"> Western festival is approaching .
(trg)="7.3"> Àjọ ̀ dún Òyìnbó ń bọ ̀ lọ ́ nà dẹ ̀ dẹ ̀ .
(src)="7.4"> To celebrate or not , that ’ s the question .
(trg)="7.4"> Kí a ṣe àjọyọ ̀ àbí kí á máà ṣe é , ìbéèrè ni ìyẹn .
(src)="7.5"> 2 .
(trg)="7.5"> 2 .
(src)="7.6"> I am Chinese and I don ’ t celebrate Western festivals .
(trg)="7.6"> Ọmọ China ni mí n kò sì kí ń ṣe àjọyọ ̀ Òyìnbó .
(src)="7.7"> 3 .
(trg)="7.7"> 3 .
(src)="7.8"> Say no to the celebration of Western festivals on the school campus .
(trg)="7.8"> Sọ pé rárá fún ìṣàjọyọ ̀ àjọ ̀ dún Òyìnbó nínú ọgbà ilé-ìwé .
(src)="7.9"> 4 .
(trg)="7.9"> 4 .
(src)="7.10"> The party-state has banned Western festivals .
(trg)="7.10"> Ẹgbẹ ́ òṣèlú-ìpínlẹ ̀ ti kọ ẹ ̀ yìn sí àjọ ̀ dún Òyìnbó .
(src)="7.11"> The celebration of festivals is now a political issue .
(trg)="7.11"> Àjọyọ ̀ àjọ ̀ dún ti wa di ọ ̀ rọ ̀ ìṣèlú .
(src)="8.1"> In addition to Christmas , the list of Western festivals also includes Valentine ’ s Day , Easter and Halloween , among others .
(trg)="8.1"> Láfikún-un Kérésìmesì , àkàsílẹ ̀ àwọn àjọ ̀ dún Òyìnbó kò yọ Àyájọ ́ Ọjọ ́ Olólùfẹ ́ , Àjíǹde àti Halowíìnì , àti bẹ ́ ẹ ̀ bẹ ́ ẹ ̀ lọ sí ẹ ̀ yìn .
(src)="8.2"> A majority of the commentaries define Western festivals as “ cultural invasion ” or “ national humiliation ” .
(trg)="8.2"> Ọ ̀ pọ ̀ lọpọ ̀ ènìyàn ni ó ka àjọ ̀ dún sí " ìgbógunti àṣà " tàbí " ìrẹ ̀ sílẹ ̀ ìlú " .
(src)="9.1"> For example , a widely circulated one said :
(trg)="9.1"> Fún àpẹẹrẹ , ọ ̀ kan tí ó ràn ká bí ìgbà tí iná bá ń jó pápá inú ọyẹ ́ sọ wípé :
(src)="9.2"> If people of a nation are too enthusiastic in celebrating other nations ’ festivals , it indicates that the country is suffered from extremely serious cultural invasion .
(trg)="9.2"> Bí àwọn ènìyàn ìlú kan bá mú àjọyọ ̀ àjọ ̀ dún ìlú mìíràn ní òkúnkúndùn ju bí ó ṣe yẹ , èyí fi hàn wípé orílẹ ̀ -èdè náà ń jẹ ìyà ìgbógunti àṣà .
(src)="9.3"> If party members and government officials are not aware of this , it means that they are not politically sensitive and have lost their progressiveness .
(trg)="9.3"> Bí ẹlẹ ́ gbẹ ́ olóṣèlú kò bá mọ èyí , a jẹ ́ wípé wọn kò ní ìkọbiarasí ìṣèlú wọ ́ n sì ti pàdánù ìlọsíwájúu wọn .
(src)="9.4"> The commentary references the history of the Eight-Nation Alliance , a coalition formed in response to the Boxer Rebellion in China between 1899 and 1901 when Chinese peasants rose up against foreign , colonial , Christian rule and culture .
(trg)="9.4"> Awuyewuye náà tọ ́ ka sí ìṣẹ ̀ lẹ ̀ -àtẹ ̀ yìnwá Eight-Nation Alliance , ẹgbẹ ́ ìṣọ ̀ kan tí a dá ní ìdáhùnsí Tẹ ̀ mbẹ ̀ lẹ ̀ kun Akànṣẹ ́ ní China láàárín-in ọdún 1899 àti 1901 nígbàtí àwọn àgbẹ ̀ rokoroko fi ẹ ̀ hónú hàn sí ìjọba amúnisìn , ètò ìṣèlú ní ìlànà Krìstẹ ́ nì àti àṣà .
(src)="9.5"> It further argues that the birthday of Mao Zedong , the founding father of the People 's Republic of China , should be treated as China ’ s Christmas :
(trg)="9.5"> Síwájú sí i , ó ní wípé ọjọ ́ ìbíi Mao Zedong , bàbá ìsàlẹ ̀ Ìlú-tí-kò-fi-ọba-jẹ ti Èèyàn-an China , ni ó yẹ kí a kà sí Kérésìmesì ìlú China :
(src)="9.7"> We should make his birthday Chinese Christmas .
(trg)="9.7"> A gbọdọ ̀ sọ ọjọ ́ ìbíi rẹ ̀ di Kérésìmesì China .
(src)="9.8"> Act and reject Western festivals .
(trg)="9.8"> Gbé ìgbésẹ ̀ kí o kọ àjọ ̀ dún Òyìnbó .
(src)="9.9"> But many on Weibo found these arguments illogical .
(trg)="9.9"> Àmọ ́ àwọn ènìyàn kan lórí Weibo kò rí ọ ̀ rọ ̀ ọlọgbọ ́ n kankan nínú àríyànjiyàn wọ ̀ nyí .
(src)="9.10"> One commentator said :
(trg)="9.10"> Ẹnìkan sọ pé :
(src)="9.11"> When Westerners celebrate the Chinese Lunar New Year , Chinese people are so proud and see the phenomena as the revival of Chinese traditional culture ...
(trg)="9.11"> Bí àwọn Òyìnbó bá ń ṣe àjọyọ ̀ Ọdún Òṣùpá Tuntun , àwọn aráa China á gbéraga wọ ́ n á sì rí èyí gẹ ́ gẹ ́ bí ìdàgbà ìsọjí àṣà ìbílẹ ̀ China ...
(src)="9.12"> When Chinese people celebrate Western festivals , what 's the point of labeling them as culture invasion ?
(trg)="9.12"> Bí àwọn aráa China bá ṣe àjọyọ ̀ àjọ ̀ dún Òyìnbó , kí ni ìdí tí a fi kà wọ ́ n sí ìgbógunti àṣà ?
(src)="9.13"> Young people celebrate Western festivals for fun and joy .
(trg)="9.13"> Àwọn ọ ̀ dọ ́ máa ń ṣe àjọyọ ̀ àjọ ̀ dún Òyìnbó nítorí àríyá àti fún ayọ ̀ .
(src)="9.14"> The festivals can boost consumption , what ’ s wrong with that ?
(trg)="9.14"> Àwọn àjọ ̀ dún wọ ̀ nyí lè mú ìkóúnjẹjẹ gbòòrò , kí ni ó burú nínú ìyẹn ?
(src)="10.1"> Some people try to draw connection between celebrating Christmas and the national humiliation that happened 160 years ago .
(trg)="10.1"> Àwọn kan gbèrò wọ ́ n fẹ ́ gbé àjọyọ ̀ Kérésìmesì fi ẹ ̀ gbẹ ́ kan ẹ ̀ gbẹ ́ pẹ ̀ lú ìrẹ ̀ sílẹ ̀ ìlú tí ó wáyé ní 160 ọdún sẹ ́ yìn .
(src)="10.2"> For what ?
(trg)="10.2"> Fún kí ni ?
(src)="10.3"> Social pressure , self-censorship
(trg)="10.3"> Ẹgbẹ ́ kíkó , ìkóraẹni-níjàánu
(src)="10.4"> The flood of anti-Christmas comments on social media has generated pressure for some social media users to self-censor .
(trg)="10.4"> Àgbàrá òdì ọ ̀ rọ ̀ sí Kérésìmesì ti ṣàn gba orí ẹ ̀ rọ-alátagbà ó sì ti mú kí àwọn òǹlò kan ó kó ara wọn ní ìjánu .
(src)="10.5"> A Weibo user expressed frustration :
(trg)="10.5"> Ònlo Weibo kan fi ẹ ̀ hónú hàn :
(src)="10.6"> Christmas is approaching .
(trg)="10.6"> Kérésìmesì ń bọ ̀ lọ ́ nà dẹ ̀ dẹ ̀ .
(src)="10.7"> In my friend circle , anti-Western festival camps and anti-anti Western festival camps are debating .
(trg)="10.7"> Ní agbo ọ ̀ rẹ ́ ẹ wa , àgọ ́ alòdìsí àjọ ̀ dún Òyìnbó àti alòdìsí alòdìsí àjọ ̀ dún Òyìnbó ń ṣe àríyànjiyàn .
(src)="10.8"> Whether one likes to celebrate or not is none of others ’ business , why do people just have to force others to agree with their view ?
(trg)="10.8"> Kò kan ẹnikéni bóyá èèyàn féràn àjọyọ ̀ tàbí kò fẹ ́ , kí ni ó dé tí àwọn ènìyàn ṣe fẹ ́ ràn láti máa fi túláàsì mú ẹlòmíràn gba èròńgbà ti wọn ?
(src)="10.9"> Everyone standing on one side is too crowded .
(trg)="10.9"> Ojú kan tí gbogbo ènìyàn dúró sí ti kún .
(src)="10.10"> For those of us who are in the middle , in order to create a balance , we have to stand on the other side .
(trg)="10.10"> Fún àwa tí a wà láàárín , kí a ba mú un dọ ́ gba , a ní láti dúró sí ẹ ̀ gbẹ ́ kejì .
(src)="10.11"> School notice against the celebration of Western festivals on campus .
(trg)="10.11"> Ìkìlọ ̀ lórí ìtako àjọ ̀ dún Òyìnbó ní inú ọgbà ilé-ìwé .
(src)="11.1"> Pressure goes beyond social media platforms , extending to institutions such as schools and corporations .
(trg)="11.1"> Awuyewuye ti kọjáa ti gbàgede orí ẹ ̀ rọ-alátagbà , ó kàn dé ilé-ìwé àti àjọ ìlú .
(src)="12.1"> Some Weibo users have shared school notices that were distributed to students .
(trg)="12.1"> Àwọn òǹlo Weibo kan ti pín ìkìlọ ̀ ilé-ìwé ti a fún akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ .
(src)="12.2"> One of the notices ( right ) refers to the " Suggestions " mandate and urges teachers and students to resist Western style celebrations .
(trg)="12.2"> Ọ ̀ kan nínú ìkìlọ ̀ náà ( ọ ̀ tún ) ń tọ ́ ka sí òfin " Ìmọ ̀ ràn " ó sì rọ olùkọ ́ àti akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ láti kọ àyájọ ́ tí ó fi ara jọ ti Òyìnbó sílẹ ̀ .
(src)="14.1"> One mother was surprised to find her child rejecting her offer of a Christmas gift .
(trg)="14.1"> Ìyàlẹ ́ nu ni ó jẹ ́ fún ìyá kan nígbàtí ọmọọ rẹ ̀ kọ ẹ ̀ bùn Kérésìmesì .
(src)="14.2"> She wrote on Weibo :
(trg)="14.2"> Ìyá kọ sórí Weibo :
(src)="14.3"> Mother : Baby , what do you want for Christmas gift ?
(trg)="14.3"> Ìyá : Ọmọ mi , ẹ ̀ bùn wo lo fẹ ́ fún Kérésìmesì ?
(src)="15.1"> Child : I will not celebrate Western festivals Christmas is not a Chinese people ’ s festival .
(trg)="15.1"> Ọmọ : Èmi ò ní ṣe àjọyọ ̀ àjọ ̀ dún Òyìnbó kì í ṣe àjọ ̀ dún ìlúu China .
(src)="16.1"> OK , you are definitely an obedient baby of the Party and the People .
(trg)="16.1"> Ó dáa , dájúdájú onígbọràn ọmọ ẹgbẹ ́ òṣèlú àti àwọn ará ìlú ni ọ ́ .
(src)="16.2"> However , high school and college students were more critical .
(trg)="16.2"> Síbẹ ̀ , àwọn akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ ilé-ẹ ̀ kọ ́ gíga ṣe àròjinlẹ ̀ .
(src)="16.3"> One student questioned school policy on Weibo :
(trg)="16.3"> Akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ kan ní ìbéèrè lórí òfin ilé-ìwé lórí Weibo :
(src)="16.4"> The school has banned Christmas decorations on campus and forbidden students to exchange gifts so as to campaign against Western festivals .
(trg)="16.4"> Ilé-ìwé ti gbé ẹsẹ ̀ lé ìṣẹ ̀ ṣọ ́ ọ Kérésìmesì nínú ọgbà ó sì ti sọ pàṣìpàrọ ̀ ẹ ̀ bùn di èèwọ ̀ ní ìpolongo ìtako àjọ ̀ dún Òyìnbó .
(src)="16.5"> Are all these measures to enhance and promote Chinese culture or a sign of losing confidence on one ’ s own culture ?
(trg)="16.5"> Ǹjẹ ́ fún ìdàgbàsókè àṣà ilẹ ̀ China ni gbogbo ọ ̀ nà yìí tàbí àmì ìpàdánù ìgbẹ ́ kẹ ̀ lé àṣà ìbílẹ ̀ ẹni ?
(src)="16.6"> Some have chosen to celebrate the festival in secret .
(trg)="16.6"> Àwọn kan ti yan ìṣàjọyọ ̀ àjọ ̀ dún náà ní ìkọ ̀ kọ ̀ .
(src)="16.7"> A Weibo user said :
(trg)="16.7"> Òǹlo Weibo kan sọ :
(src)="16.8"> The company has forbidden the celebration of Western festivals .
(trg)="16.8"> Ilé-iṣẹ ́ ti sọ ayẹyẹ àjọyọ ̀ àjọ ̀ dún Òyìnbó di èèwọ ̀ .
(src)="16.9"> But the secretary in the personnel department has handed out a Christmas apple to the staff members in secret .
(trg)="16.9"> Ṣùgbọ ́ n akọ ̀ wé láti ẹ ̀ ka ètò-òṣìṣẹ ́ ti fi òró Kérésìmesì ( ẹ ̀ bùn Kérésìmesì tí ó wọ ́ pọ ̀ ) fún àwọn òṣìṣẹ ́ ní ìkọ ̀ kọ ̀ .
(src)="16.10"> Let ’ s wish for peace .
(trg)="16.10"> Ẹ jẹ ́ kí a fẹ ́ àlàáfíà .
(src)="16.11"> Another Weibo user expressed his view with a Christmas wish :
(trg)="16.11"> Òǹlo Weibo mìíràn fi èròńgbàa rẹ ̀ hàn pẹ ̀ lú ohun tí ó fẹ ́ fún Kérésìmesì :
(src)="16.12"> Merry Christmas !
(trg)="16.12"> Ẹ kú ọdún Kérésìmesì !
(src)="16.13"> I love you god !
(trg)="16.13"> Mo nífẹ ̀ ẹ ́ -ẹ ̀ rẹ olúwa !
(src)="16.14"> Santa Claus , pls give me a big big sock with freedom in it .
(trg)="16.14"> Bàba Kérésìmesì , jọ ̀ wọ ́ fún mi ní ìbọsẹ ̀ nílá gbàngbà pẹ ̀ lú òmìnira nínúu rẹ ̀ .
# en/2018_10_12_why-are-african-governments-criminalising-online-speech-because-they-fear-its-power_.xml.gz
# yo/2018_12_28_115_.xml.gz
(src)="1.1"> Why are African governments criminalising online speech ?
(trg)="1.1"> Kí ló dé tí ìjọba Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ ń f 'òfin de ọ ̀ rọ ̀ sísọ orí-ayélujára ?
(src)="1.2"> Because they fear its power . · Global Voices
(trg)="1.2"> Nítorí wọ ́ n bẹ ̀ rù agbára rẹ ̀ .
(src)="1.3"> Students at Haromaya University in Ethiopia displaying a quasi-official anti-government gesture .
(trg)="1.3"> Akẹ ́ kọ ̀ ọ ́ Ifásitì Haromaya ní Ethiopia ń fi àmì ìtako ìjọba hàn .
(src)="1.4"> Photo shared widely on social media .
(trg)="1.4"> Àwòrán tí a pín lórí ẹ ̀ rọ-alátagbà .
(src)="2.1"> Africa ’ s landscape of online free speech and dissent is gradually , but consistently , being tightened .
(trg)="2.1"> Ọ ̀ rọ ̀ sísọ lórí ayélujára ti ń rí ìfúnpa láti ọwọ ́ ìjọba díẹ ̀ díẹ ̀ .
(src)="2.2"> In legal and economic terms , the cost of speaking out is rapidly rising across the continent .
(trg)="2.2"> Nínú ìlànà òfin àti ọ ̀ rọ ̀ Ajé , iye òmìnira ọ ̀ rọ ̀ ń dìde kárí Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ .
(src)="3.1"> While most governments are considered democratic in that they hold elections with multi-party candidates and profess participatory ideals , in practice , many operate much closer dictatorships — and they appear to be asserting more control over digital space with each passing day .
(trg)="3.1"> Nígbà tí àwọn ìjọba kan mọ rírì ètò ìjọba àwa-arawa nípasẹ ̀ ṣíṣe ìbò pẹ ̀ lú ọlọ ́ pọ ̀ -ẹgbẹ ́ òṣèlú àti sọ nígbangba nípa àjọṣe , nínú ìṣe , ọ ̀ pọ ̀ máa ń lo àṣẹ tí ò ṣe é yí padà — wọ ́ n sì ń lo agbára àṣẹ yìí lórí ẹ ̀ rọ-ayárabíàṣá bí ọjọ ́ ṣe ń gun orí ọjọ ́ .
(src)="4.2"> Media workers and citizens have been jailed on charges ranging from publishing “ false information ” to exposing state secrets to terrorism .
(trg)="4.2"> Òṣìṣẹ ́ ìròyìn àti àwọn ọmọ-ìlú ti di èrò àtìmọ ́ lé lórí ẹ ̀ sùn àtẹ ̀ jáde " ìròyìn irọ ́ " títí kan ìkóròyìn ìkòkọ ̀ ìlú sí etí ìgbọ ́ ẹgbẹ ́ afẹ ̀ míṣòfò .
(src)="5.1"> At the recent Forum of Internet Freedom in Africa ( FIFA ) held in Accra , Ghana , a group of panelists from various African countries all said they feared African governments were interested in controlling digital space to keep citizens in check .
(trg)="5.1"> Ní ibi Àpérò Òmìnira Ẹ ̀ rọ-ayélujára ní Ilẹ ̀ -Adúláwọ ̀ ( FIFA ) tí ó wáyé ní Accra , Ghana , ikọ ̀ akópa láti àwọn ìlú ilẹ ̀ Adúláwọ ̀ pátá sọ wípé kò ní ṣe ẹnu rere bí ìjọba bá fi òfin de ọmọ-ìlú tí ó ń lo ẹ ̀ rọ-ayárabíaṣá .
(src)="6.1"> Many countries have statutes and laws which guarantee the right to free expression .
(trg)="6.1"> Ọ ̀ pọ ̀ orílẹ ̀ -èdè ló ní àwọn òfin àti àbádòfin tí ó fún ọmọ ènìyàn ní ẹ ̀ tọ ́ sí òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ .
(src)="6.2"> In Nigeria , for example , the Freedom of Information Act grants citizens the right to demand information from any government agency .
(trg)="6.2"> Ní Nàìjíríà , fún àpẹẹrẹ , Àbádòfin Òmìnira Ọ ̀ rọ ̀ fún ọmọ ìlú ní òmìnira láti béèrè fún ìwífun lọ ́ wọ ́ àjọ ìjọba .
(src)="7.1"> Yet , Nigeria has issued other laws that authorities use to deny these aforementioned rights .
(trg)="7.1"> Síbẹ ̀ , Nàìjíríà tí tẹ àwọn òfin kan tí ó tẹ orí àwọn ẹ ̀ tọ ́ òkè yìí bọlẹ ̀ .
(src)="9.1"> Making laws with ambiguous and subjective terms like " inconvenience " or " insult " calls for concern .
(trg)="9.1"> Ìṣòfin àìdájú àti àwọn gbólóhùn bíi " ìnira " tàbí " ìwọ ̀ sí " jẹ ́ nǹkan tí a ní láti mójútó .
(src)="9.2"> Governments and their agents often use this as a cover to suppress freedom of expression .
(trg)="9.2"> Ìjọba àti àwọn àjọ rẹ ̀ máa ń sábà fi èyí ṣe bójúbójú fún ìtẹríbọlẹ ̀ òmìnira ọ ̀ rọ ̀ sísọ .
(src)="10.1"> Who determines the definition of an insult ?
(trg)="10.1"> Ta ni ẹni tí ó ń sọ bóyá ọ ̀ rọ ̀ kan jẹ ́ àfojúdi ?
(src)="10.2"> Should public officials expect to develop a thick skin ?
(trg)="10.2"> Ǹjẹ ́ ó yẹ kí òṣìṣẹ ́ ìjọba ó ṣe ìmúdàgbà àwọ ̀ -ara tí ó ní ipọn ?