# bbc/2015241.xml.gz
# yo/2015241.xml.gz


(src)="1"> Daftar Isi
(trg)="1"> Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

(src)="2"> © 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
(trg)="2"> © 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

(src)="8"> Songon dia do Solhot ni Paralealeon Muna tu Jahowa ?
(trg)="3"> Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ?

(src)="13"> 3
(trg)="4"> 3

(src)="14"> Ulaon Marsiajar Bibel tu Sude 4
(trg)="5"> Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì fún Gbogbo Èèyàn 4

(src)="15"> Parningotan Ari Hamamate ni Jesus Boasa Ringkot Taulahon ?
(trg)="8"> Ìjíròrò Láàárín Ẹlẹ́rìí Jèhófà àti Ẹnì Kan Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Máa Ṣe Ìrántí Ikú Jésù ?

(src)="16"> 29
(trg)="9"> 12

(src)="17"> Sungkunsungkun na Dialusi Bibel 32
(trg)="11"> 15
(trg)="12"> Ohun Tí Bíbélì Sọ 16

# bbc/2015242.xml.gz
# yo/2015242.xml.gz


(src)="1"> TOPIK UTAMA | SIULASON NI MAJALAH ON
(trg)="1"> KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ | ṢÉ WÀÁ FẸ́ KẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ ?

(src)="2"> Aha do na tinuju ni ngolu on ?
(trg)="2"> Kí nìdí tá a fi wà láyé ?

(src)="3"> Boasa marsitaonon jala mate jolma ?
(trg)="3"> Kí nìdí tá a fi ń jìyà tá a sì ń kú ?

(src)="4"> Aha do panghirimon tu ari na naeng ro ?
(trg)="4"> Kí ló máa ṣẹlẹ̀ ní ọjọ́ ọ̀la ?

(src)="5"> Disarihon Debata do hita ?
(trg)="5"> Ṣé Ọlọ́run bìkítà nípa mi ?

(src)="6"> Hea do tubu di rohamu sungkunkungkun sisongon on ?
(trg)="6"> Ǹjẹ́ o ti bi ara rẹ ní irú àwọn ìbéèrè yìí rí ?

(src)="7"> Molo hea , ndang holan hamu na songon i .
(trg)="7"> Tó bá jẹ́ bẹ́ẹ̀ , mọ̀ pé kì í ṣe ìwọ nìkan lo ní irú èrò bẹ́ẹ̀ .

(src)="8"> Torop halak di liat portibi on mangarimangi sungkunsungkun na ringkot on .
(trg)="8"> Kárí ayé làwọn èèyàn ti ń wá ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè tó ṣe pàtàkì nígbèésí ayé .

(src)="9"> Boi do tadapot alusna ?
(trg)="9"> Ǹjẹ́ o lè rí ìdáhùn ?

(src)="10"> Marjuta halak mandok , ” Boi ! ”
(trg)="10"> Ọ̀pọ̀ èèyàn máa dáhùn pé , “ Bẹ́ẹ̀ ni ! ”

(src)="11"> Boasa ?
(trg)="11"> Kí nìdí ?

(src)="12"> Alana nunga dapot nasida alus na pas tu sungkunsungkun na sian Bibel .
(trg)="12"> Ìdí ni pé wọ́n ti rí àwọn ìdáhùn tó tẹ́ wọn lọ́rùn nínú Bíbélì .

(src)="13"> Lomo do rohamu mamboto aha na didok ni Bibel ?
(trg)="13"> Ṣé wàá fẹ́ mọ ohun tí Bíbélì sọ ?

(src)="14"> Jala hamu pe boi mandapot laba sian parsiajaran Bibel na so manggarar na pinarade ni Sitindangi Ni Jahowa .
(trg)="14"> Tó o bá fẹ́ bẹ́ẹ̀ , ẹ̀kọ́ Bíbélì tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń kọ́ àwọn èèyàn lọ́fẹ̀ẹ́ máa ṣe ẹ́ láǹfààní .

(src)="15"> *
(trg)="15"> *

(src)="16"> Tutu do , tingki mangalului alusna sian Bibel , deba mandok : ” Ndang adong tingkingku . ”
(trg)="16"> Tó bá kan pé ká kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì , àwọn kan máa ń sọ pé : “ Mi ò kì í ráyè . ”

(src)="17"> ” Maol hian antusan . ”
(trg)="17"> “ Ó ti le jù . ”

(src)="18"> Adong muse na mandok ” Annon sai ro hamu ! ”
(trg)="18"> “ Mi ò fẹ́ràn kí n máa ṣàdéhùn . ”

(src)="19"> Alai na deba nai asing muse do pandapotna .
(trg)="19"> Àmọ́ , èrò àwọn míì yàtọ̀ síyẹn .

(src)="20"> Dilehon nasida tingkina laho mangantusi aha na diajarhon ni Bibel .
(trg)="20"> Wọ́n gbà láti kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì .

(src)="21"> Taida ma pigapiga pangalaman :
(trg)="21"> Jẹ́ ká wo àwọn àpẹẹrẹ mélòó kan :

(src)="22"> ” Nunga lao ahu tu gareja Katolik dohot Protestan , Kuil ugamo Hindu , dohot Wihara ugamo Budha , jala marsingkola di singkola teologia .
(trg)="22"> “ Mo ti lọ sí ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì àti ti Pùròtẹ́sítáǹtì , mo lọ sí tẹ́ńpìlì àwọn ẹlẹ́sìn Sikh , mo ṣe ẹ̀sìn Búdà , mo sì lọ kẹ́kọ̀ọ́ ìsìn ní yunifásítì .

(src)="23"> Alai godang dope sungkunsungkunku taringot Debata na so taralusi .
(trg)="23"> Àmọ́ , mi ò rí ìdáhùn sí ọ̀pọ̀ ìbéèrè tó ń jẹ mí lọ́kàn .

(src)="24"> Dung i ro ma sahalak Sitindangi Ni Jahowa tu jabungku .
(trg)="24"> Lọ́jọ́ kan , Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan wá sí ilé mi .

(src)="25"> Lomo rohangku manangihon alusna na sian Bibel , gabe olo ma ahu marsiajar Bibel . ” ​ — Gill , Inggris .
(trg)="26"> Èyí sì mú kí n gbà láti kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì . ” — Gill , ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì .

(src)="26"> ” Godang do sungkunsungkunku taringot hangoluan , alai pastor di gareja nami ndang mangalehon alus na pas .
(trg)="27"> “ Mo ní ọ̀pọ̀ ìbéèrè nípa ìgbésí ayé , àmọ́ pásítọ̀ ṣọ́ọ̀ṣì mi kò fún mi ní ìdáhùn tó tẹ́ mi lọ́rùn .

(src)="27"> Alai sahalak Sitindangi Ni Jahowa mangalusi sungkunsungkunhu mamangke Bibel .
(trg)="28"> Àmọ́ , Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan fi Bíbélì nìkan dáhùn àwọn ìbéèrè mi .

(src)="28"> Tingki disungkun halak i tu ahu olo dope mangantusi na asing , las rohangku mangoloi . ” ​ — Koffi , Benin .
(trg)="29"> Nígbà tó béèrè bóyá máa fẹ́ kẹ́kọ̀ọ́ sí i , tayọ̀tayọ̀ ni mo gbà . ” — Koffi , Benin .

(src)="29"> ” Nunga leleng sungkunsungkun rohangku songon dia do panghilalaan ni halak naung mate .
(trg)="30"> “ Mo fẹ́ mọ ohun tó ń ṣẹlẹ̀ sáwọn tó ti kú .

(src)="30"> Porsea do ahu ndang adong be pardomuan ni na mate tu na mangolu , alai lomo rohangku mamboto songon dia alus ni Bibel .
(trg)="31"> Mo gbà pé àwọn òkú lè ṣe àwọn èèyàn ní jàǹbá , àmọ́ ó wù mí láti mọ ohun tí Bíbélì sọ nípa rẹ̀ .

(src)="31"> Alani i , marsiajar Bibel ma ahu tu donganku sahalak Sitindangi . ” ​ — José , Brasil .
(trg)="32"> Torí náà , mo bẹ̀rẹ̀ sí í kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́dọ̀ ọ̀rẹ́ mi tó jẹ́ Ẹlẹ́rìí Jèhófà . ” — José , Brazil .

(src)="32"> ” Sai hujahai Bibel alai ndang boi huantusi .
(trg)="33"> “ Mo ka Bíbélì , àmọ́ ohun tí mo kà kò yé mi .

(src)="33"> Dung i ro ma Sitindangi Ni Jahowa jala tangkas ma dipatorang angka surirang ni Bibel .
(trg)="34"> Lọ́jọ́ kan , àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà wá sọ́dọ̀ mi , wọ́n sì ṣàlàyé àwọn àsọtẹ́lẹ̀ Bíbélì mélòó kan fún mi .

(src)="34"> Lomo dope rohangku laho mangantusi angka na asing . ” ​ — Dennize , Meksiko .
(trg)="35"> Èyí mú kó wù mí láti mọ̀ sí i . ” — Dennize , Mẹ́síkò .

(src)="35"> ” Sungkunsungkun do rohangku , disarihon Debata do ahu ?
(trg)="36"> “ Mo máa ń ronú pé bóyá ni Ọlọ́run bìkítà nípa mi .

(src)="36"> Dung i martangiang ma ahu tu Debata na adong di Bibel .
(trg)="37"> Torí náà , mo gbàdúrà sí Ọlọ́run tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀ .

(src)="37"> Marsogot nai dituktuk Sitindangi ma pintu ni jabungku jala huoloi ma marsiajar Bibel . ” ​ — Anju , Nepal .
(trg)="38"> Ní ọjọ́ kejì , àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà wá sílé mi , mo sì gbà láti kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì . ” — Anju , Nepal .

(src)="38"> Sude pangalaman on paingothon hita tu hata ni Jesus : ” Martua ma na umboto na pogos partondionna . ”
(trg)="39"> Àwọn ìrírí yìí rán wa létí ohun tí Jésù sọ pé : “ Aláyọ̀ ni àwọn tí àìní wọn nípa ti ẹ̀mí ń jẹ lọ́kàn . ”

(src)="39"> Tutu , nunga disuanhon hian di roha ni sude jolma asa manarihon na porlu tu partondion .
(trg)="40"> Ká sòótọ́ , ó máa ń wù wá láti mọ Ọlọ́run .

(src)="40"> Holan Debata do na boi manggohi haporluon i , marhite hataNa , i ma Bibel .
(trg)="41"> Ọlọ́run nìkan sì lẹni tó lè mú ká mọ òun nípasẹ̀ Bíbélì , Ọ̀rọ̀ rẹ̀ .

(src)="41"> Aha do na hombar tu marsiajar Bibel ?
(trg)="42"> Báwo la ṣe ń ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ?

(src)="42"> Aha do labana tu hita ?
(trg)="43"> Ọ̀nà wo ni ẹ̀kọ́ yìí máa gbà ṣe ẹ́ láǹfààní ?

(src)="43"> Dialusi ma sungkunsungkun on di artikel na mangihut .
(trg)="44"> A máa rí ìdáhùn sí àwọn ìbéèrè yìí nínú àpilẹ̀kọ tó tẹ̀ lé èyí .

(src)="44"> Jahowa i ma goar ni Debata songon na disurat di Bibel .
(trg)="45"> Bíbélì jẹ́ ká mọ̀ pé Jèhófà ni orúkọ Ọlọ́run .

(src)="45"> GOARNA : Sian hata Junani bi·bliʹa , lapatanna ” punguan ni angka buku ”
(trg)="46"> ORÚKỌ : Látinú ọ̀rọ̀ Gíríìkì náà bi·bliʹa , tó túmọ̀ sí “ àwọn ìwé kéékèèké ”

(src)="46"> ISINA : 39 buku di hata Heber ( na deba marhata Aram ) dohot 27 marhata Junani
(trg)="47"> OHUN TÓ WÀ NÍNÚ RẸ̀ : Ìwé 39 ní èdè Hébérù ( pẹ̀lú ojú ìwé mélòó kan ní èdè Árámáíkì ) àti ìwé 27 ní èdè Gíríìkì

(src)="47"> PANURAT : Hirahira 40 halak manurat saleleng 1.600 taon , sian taon 1513 ASM sahat tu 98 DM *
(trg)="48"> BÍ WỌ́N ṢE KỌ Ọ́ : Nǹkan bíi 40 èèyàn ló kọ ọ́ , ó sì gbà ju 1,600 ọdún lọ , bẹ̀rẹ̀ láti ọdún 1513 Ṣ.S.K . sí nǹkan bí ọdún 98 S.K .
(trg)="49"> *

(src)="48"> HATA : Nunga disalin deba manang sude tu lobi sian 2.500 hata
(trg)="50"> IYE ÈDÈ : Ó ti wà lápá kan tàbí lódindi ní èdè tó lé ní 2,500

(src)="49"> DISARHON : Buku na gumodang tarsar di liat portibi on hirahira lima miliar Bibel
(trg)="51"> ÌPÍNKIRI : Wọ́n ti tẹ nǹkan bíi bílíọ̀nù mẹ́rin Bíbélì , èyí mú kó jẹ́ ìwé tí wọ́n tíì pín kiri jù lọ kárí ayé

(src)="50"> ASM hata na dipajempek lapatanna ” Andorang So Masehi ” , dohot DM lapatanna ” Dunghon Masehi ”
(trg)="52"> Ìkékúrú yìí Ṣ.S.K . túmọ̀ sí “ Ṣáájú Sànmánì Kristẹni . ”
(trg)="53"> S.K . sì túmọ̀ sí “ Sànmánì Kristẹni . ”

# bbc/2015243.xml.gz
# yo/2015243.xml.gz


(src)="1"> TOPIK UTAMA | SIULASON NI MAJALAH ON
(trg)="1"> KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ | ṢÉ WÀÁ FẸ́ KẸ́KỌ̀Ọ́ BÍBÉLÌ ?

(src)="2"> Sitindangi Ni Jahowa ditanda alani ulaon marbarita na uli .
(trg)="2"> Àwọn èèyàn mọ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà dáadáa nítorí iṣẹ́ ìwàásù tá à ń ṣe .

(src)="3"> Alai diboto hamu do hami pe ditanda ala patupahon ulaon parsiajaran Bibel di liat portibi on ?
(trg)="3"> Àmọ́ , ǹjẹ́ o mọ̀ pé a tún máa ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé ?

(src)="4"> Di taon 2014 , lobi sian 8.000.000 Sitindangi di 240 Negara mambahen hirahira 9.500.000 parsiajaran Bibel ganup bulan .
(trg)="4"> Lọ́dún 2014 , ó lé ní mílíọ̀nù mẹ́jọ [ 8,000,000 ] àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní orílẹ̀ - èdè òjìlérúgba [ 240 ] tó ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lóṣooṣù .

(src)="5"> * Boi dohonon , godang ni halak na marsiajar Bibel dohot hami lobi sian bilangan ni pangisi ni 140 negara !
(trg)="6"> * Ká sòótọ́ , iye àwọn tá à ń kọ́ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ju iye àwọn èèyàn tó ń gbé ní ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn orílẹ̀ - èdè tó fẹ́rẹ̀ẹ́ tó ogóje [ 140 ] !

(src)="6"> Laho patupahon ulaon pangajarion on , ganup taon Sitindangi Ni Jahowa pabinsarhon hirahira sada satonga miliar Bibel , buku , majalah , dohot angka na asing na dipangke tu parsiajaran Bibel di bagasan 700 hata !
(trg)="7"> Kí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà lè ṣe iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ yìí , a máa ń tẹ Bíbélì , àwọn ìwé , àwọn ìwé ìròyìn àtàwọn ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì míì tó fẹ́rẹ̀ẹ́ tó bílíọ̀nù kan ààbọ̀ ní nǹkan bí ọgọ́rùn - ún méje ( 700 ) èdè !

(src)="7"> Ndang adong be na boi tarpatudos tu ulaon marbarita on i ma manogihon halak marsiajar Bibel di hatana sandiri .
(trg)="8"> Iṣẹ́ ìtẹ̀wé tí kò lẹ́gbẹ́ yìí ń jẹ́ kó ṣeé ṣe fún àwọn èèyàn láti kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì ní èdè tí wọ́n bá fẹ́ .

(src)="8"> ” Ndang hea lomo rohangku marsiajar di singkola , alai parsiajaran on tabo .
(trg)="9"> “ Nígbà tí mo wà níléèwé , mi ò fi bẹ́ẹ̀ fẹ́ràn kí n máa kẹ́kọ̀ọ́ , àmọ́ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì yìí yàtọ̀ .

(src)="9"> Jala sude na huparsiajari palashon rohangku ! ” ​ — Katlego , Afrika Selatan .
(trg)="10"> Àwọn ohun tí mo kọ́ tù mí nínú gan - an ! ” — Katlego , South Africa .

(src)="10"> ” Parsiajaran on mangalusi sude sungkunsungkunku jala godang na i dope . ” ​ — Bertha , Meksiko .
(trg)="11"> “ Ìkẹ́kọ̀ọ́ náà dáhùn gbogbo ìbéèrè tó ń jẹ mí lọ́kàn àtàwọn míì . ” — Bertha , Mẹ́síkò .

(src)="11"> ” Marsiajar Bibel dibahen di jabungku di tingki na pas di ahu .
(trg)="12"> “ Ilé mi la ti ń sẹ ìkẹ́kọ̀ọ́ náà ní àkókò tó rọrùn fún mi .

(src)="12"> Aha dope na hurang ! ” ​ — Eziquiel , Brasil .
(trg)="13"> Kí ni mo tún ń fẹ́ ! ” — Eziquiel , Brazil .

(src)="13"> ” Sipata 15 sahat 30 minut hami marsiajar — manang umleleng sian i ​ — dia ma na pas tu tingkingku . ” ​ — Viniana , Australia .
(trg)="14"> “ Nígbà míì , mo máa ń lo nǹkan bí ìṣẹ́jú mẹ́ẹ̀ẹ́dógún sí ọgbọ̀n ìṣẹ́jú láti fi kẹ́kọ̀ọ́ , nígbà míì sì rèé , a lè lò jù bẹ́ẹ̀ lọ , èyí tó bá ti rọrùn fún mi ni . ” — Viniana , Ọsirélíà .

(src)="14"> ” Ndang margarar parsiajaran i ​ — longang do roha mangida ! ” ​ — Aime , Benin .
(trg)="15"> “ Ọ̀fẹ́ ni ìkẹ́kọ̀ọ́ náà , mo sì gbádùn rẹ̀ gan - an ! ” — Aimé , Benin .

(src)="15"> ” Na mangajarhon Bibel tu ahu burju jala lambok .
(trg)="16"> “ Ẹni tó ń kọ́ mi lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì jẹ́ onísùúrù àti onínúure .

(src)="16"> Gabe maraleale ma hami . ” ​ — Karen , Irlandia Utara .
(trg)="17"> Èyí mú ká di ọ̀rẹ́ tímọ́tímọ́ . ” — Karen , Northern Ireland .

(src)="17"> ” Godang na marsiajar Bibel ndang na ingkon gabe Sitindangi Ni Jahowa . ” ​ — Denton , Inggris .
(trg)="18"> “ Ọ̀pọ̀ èèyàn ló ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì tí wọn ò sì di Ẹlẹ́rìí Jèhófà . ” — Denton , ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì .

(src)="18"> Boi tapillit na laho taparsiajari jala tapareso ayat ni Bibel na hombar tu parsiajaran i .
(trg)="19"> A máa ń yan onírúurú ẹ̀kọ́ Bíbélì , a sì máa ṣàyẹ̀wò àwọn ẹsẹ Bíbélì tó bá àwọn ẹ̀kọ́ náà mu .

(src)="19"> Songon , Bibel mangalusi angka sungkunsungkun on : Ise do Debata ?
(trg)="20"> Bí àpẹẹrẹ , Bíbélì dáhùn àwọn ìbéèrè , bíi : Ta ni Ọlọ́run ?

(src)="20"> Songon dia do hadirionNa ?
(trg)="21"> Irú ẹni wo ni Ọlọ́run jẹ́ ?

(src)="21"> Adong do goarNa ?
(trg)="22"> Ṣé ó ní orúkọ ?

(src)="22"> Didia Ibana Maringanan ?
(trg)="23"> Ibo ló ń gbé ?

(src)="23"> Boi do jonok hita tu Ibana ?
(trg)="24"> Ǹjẹ́ a lè sún mọ́ ọn ?

(src)="24"> Sungkunsungkun on manogihon hita asa mangalului alusna di Bibel .
(trg)="25"> Ohun tó máa ń jẹ́ ìṣòro ni béèyàn ṣe máa rí ìdáhùn nínú Bíbélì .

(src)="25"> Laho mangurupi halak mangalului alusna , somalna hita mamangke buku si 224 alaman i ma buku Apa yang Sebenarnya Alkitab Ajarkan ?
(trg)="26"> Kó lè ṣeé ṣe fún àwọn èèyàn láti rí ìdáhùn , a máa ń lo ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan - an ?
(trg)="27"> tó ní ojú ìwé igbà ó lé mẹ́rìnlélógún [ 224 ] .

(src)="26"> * Buku on denggan dipatupa tarlumobi laho mangurupi halak laho mangantusi aha na sasintongna diajarhon Bibel .
(trg)="28"> * Ńṣe la dìídì ṣe ìwé yìí láti ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ kí wọ́n lè lóye àwọn ẹ̀kọ́ pàtàkì nínú Bíbélì .

(src)="27"> Dohot ma i parsiajaran taringot Debata , Jesus Kristus , hasusaan ni jolma , haheheon , tangiang , dohot angka na asing dope .
(trg)="29"> Ìwé náà ní àwọn ẹ̀kọ́ tó sọ̀rọ̀ nípa Ọlọ́run , Jésù Kristi , ìyà tó ń jẹ àwa èèyàn , àjíǹde , àdúrà àtàwọn ẹ̀kọ́ míì .