# arn/2017002.xml.gz
# yo/2017002.xml.gz


(src)="1"> © 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
(trg)="1"> © 2016 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania

(src)="2"> Wülngeal tüfachi papel yeniey kiñe küdaw Biblia ñi kimeltun , femkeel kom Mapu mu , fey kulliwtukey mañum yewün mu müten .
(trg)="2"> Ìtẹ̀jáde yìí kì í ṣe títà .
(trg)="3"> Ó jẹ́ ara iṣẹ́ ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kárí ayé tá à ń fi ọrẹ àtinúwá tì lẹ́yìn .

(src)="3"> Fendengekelay .
(src)="4"> Ayülmi wülal plata , amunge ta www.jw.org .
(trg)="4"> Tó o bá fẹ́ ṣètọrẹ , jọ̀wọ́ lọ sí ìkànnì wa www.jw.org / yo .

(src)="6"> Welu Génesis , Rut ka Jona entungey Génesis , Rut y Jonás en mapudungun , Sociedad Bíblica Chilena , 1994 .
(trg)="5"> Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀ , inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun , la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò .

(src)="7"> Tati Biblia müley Griegu Wirintukun mu ( Nuevo Testamento ) , entungey Ngünechen ñi küme Dungu , Sociedades Bíblicas Unidas , 1997 , mapudungun mew .
(trg)="6"> ÌWÉ ÌRÒYÌN Ilé Ìṣọ́ yìí ń gbé Jèhófà Ọlọ́run tó jẹ́ Alákòóso ayé òun ọ̀run ga .

(src)="8"> TÜFACHI CHILLKA , Ti Werken , püramyekefi ta Chaw Ngünechen Jewba , tati kom Ngünenielu .
(trg)="7"> Ó ń fi ìhìn rere tu àwọn èèyàn nínú pé , láìpẹ́ , Ìjọba Ọlọ́run yóò fòpin sí gbogbo ìwà ibi , á sì sọ ilẹ̀ ayé di Párádísè .

(src)="9"> Kimeltukey Chaw Ngünechen ñi Ngünenien wenu mapu mülelu , pichiñma mu apümafi kom ti wedake dungu ka kiñe küme mülewe elkünutuafi ti Mapu , feymu yafültukukefi tati pu che .
(trg)="8"> Ìwé ìròyìn yìí ń gbani níyànjú láti nígbàgbọ́ nínú Jésù Kristi tó kú ká lè ní ìyè àìnípẹ̀kun .

(src)="10"> Ka kellukefi ñi feyentual ta Jesukristo mu , kidu larkelu am taiñ nieal afnoachi mongen , ka fewla Longko Ülmenküley Chaw Ngünechen ñi Ngünenien mu .
(trg)="9"> Jésù sì ti ń ṣàkóso báyìí gẹ́gẹ́ bí Ọba Ìjọba Ọlọ́run .

(src)="11"> Tüfachi chillka amuley ñi entungeel 1879 tripantu mu .
(trg)="10"> Láti ọdún 1879 la ti ń tẹ ìwé ìròyìn yìí déédéé , kì í sì í dá sí ọ̀rọ̀ ìṣèlú .

(src)="12"> Koneltukelay politiko dungu mew .
(src)="13"> Yamniekefi ti Biblia ñi doykülen .
(trg)="11"> Orí Bíbélì ni gbogbo ohun tó ń sọ dá lé .

# arn/2017003.xml.gz
# yo/2017003.xml.gz


(src)="1"> Chew ñi mülen trokiñke dungu
(trg)="1"> Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

(src)="2"> 3 ¿ Kümeafuy tañi papeltuafiel ti Biblia ?
(trg)="2"> 3 Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kó O Ka Bíbélì ?

(src)="3"> 4 ¿ Chumngechi eluwküleafun ?
(trg)="3"> 4 Ibo Ni Mo Ti Fẹ́ Bẹ̀rẹ̀ ?

(src)="4"> 5 ¿ Chumngechi doy ayüwmayafiñ ?
(trg)="4"> 5 Báwo Ni Mo Ṣe Máa Gbádùn Ẹ̀ ?

(src)="5"> 6 Tati Biblia , ¿ chumngechi kümelkayaenew tañi mongen mu ?
(trg)="5"> 6 Báwo Ni Bíbélì Ṣe Lè Tún Ayé Mi Ṣe ?

(src)="6"> 8 TI BIBLIA KÜME ELKÜNUTUEYEW ÑI MONGEN
(trg)="6"> 8 BÍBÉLÌ MÁA Ń YÍ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀWỌN ÈÈYÀN PA DÀ

(src)="7"> ¡ Ayülafun ñi layal !
(trg)="7"> Mi Ò Fẹ́ Kú O !

(src)="8"> 10 INAYENTUÑMAYAFIYIÑ ÑI MUPILTUN | ENOK
(trg)="8"> 10 TẸ̀ LÉ ÀPẸẸRẸ ÌGBÀGBỌ́ WỌN | ÉNỌ́KÙ

(src)="9"> “ Enok tuterkefi ta Ngünechen ”
(trg)="9"> “ Ó Ti Wu Ọlọ́run Dáadáa ”

(src)="10"> 14 ¿ FALIN - NGEPEY MAY ÑI WELURAKIDUAMKEN ?
(trg)="10"> 14 EWU TÓ WÀ NÍNÚ KÉÈYÀN ṢI BÍBÉLÌ LÓYE

(src)="11"> 16 ¿ CHEM KIMELTUKEY TI BIBLIA ?
(trg)="11"> 16 OHUN TÍ BÍBÉLÌ SỌ

# arn/2017004.xml.gz
# yo/2017004.xml.gz


(src)="1"> Tati Biblia ñi kuyfi tuwün - ngen mu , ¿ kellulayafeiñmu ?
(trg)="1"> Ṣé Bíbélì ṣì wúlò láyé ọ̀làjú tá a wà yìí ?

(src)="2"> Kam ¿ petu falintufalngey ?
(src)="3"> Biblia feypi : “ Kom tati wirikonkülechi dungu ti Wirin Chillka mew wiringey Ngünechen tañi adkünuel ka ñi piel mew , feymew rume kümey ” ( 2 Timotew 3 : 16 , 17 ) .
(trg)="2"> Ẹ gbọ́ ohun tí Bíbélì fúnra rẹ̀ sọ , ó ní : “ Gbogbo Ìwé Mímọ́ ni Ọlọ́run mí sí , ó sì ṣàǹfààní . ” ​ — 2 Tímótì 3 : 16 , 17 .

(src)="4"> Tüfachi chillka Ti Werken feypi kiñeke dungu pengelkelu Biblia ñi kimün taiñ kellukeetew , ka feypi chumngechi doy kümelkayafeiñmu taiñ papeltufiel Biblia .
(trg)="3"> Ìwé ìròyìn Ilé Ìṣọ́ yìí sọ díẹ̀ lára àwọn ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó wà nínú Bíbélì àti àwọn ohun tá a lè ṣe láti jàǹfààní nínú Bíbélì kíkà .

# arn/2017005.xml.gz
# yo/2017005.xml.gz


(src)="1"> WÜNEN PAGINA ÑI PENGELNIEEL | CHUMNGECHI DOY KÜMELKAYAFEYMU TAMI PAPELTUFIEL BIBLIA
(trg)="1"> KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ | BÓ O ṢE LÈ RÍ Ẹ̀KỌ́ KỌ́ LÁTINÚ KÍKA BÍBÉLÌ

(src)="2"> “ Küdawngelu ñi adümngeal tati Biblia trokifiñ ” ( Jovy ) .
(trg)="2"> “ Èrò mi ni pé ó máa ṣòro fún mi láti lóye Bíbélì . ” ​ — Jovy

(src)="3"> “ Rakiduamkefun ñi afeluwün - ngen ” ( Queennie ) .
(trg)="3"> “ Mo ronú pé kíka Bíbélì kì í gbádùn mọ́ni . ” ​ — Queennie

(src)="4"> “ Ngüneduamlu ñi fenterupan ti Biblia , duamwelan ñi papeltuafiel ” ( Esekiel ) .
(trg)="4"> “ Nígbà tí mo bá rí bí Bíbélì ṣe tóbi tó , ńṣe ló máa ń sú mi . ” ​ — Ezekiel

(src)="5"> Küpa papeltufuymi chi tati Biblia , welu tami rakiduamken mu tüfachi che reke , duamwelaymi chi tami femal .
(trg)="5"> Ṣé o ti ronú nípa kíka Bíbélì , àmọ́ tí o kò kà á torí pé o ní irú èrò tí àwọn tá a sọ̀rọ̀ wọn lókè yìí ní ?

(src)="6"> Fentren che afeluwün - ngelu trokikefingün ñi papeltufiel Biblia .
(trg)="6"> Kíka Bíbélì máa ń ka ọ̀pọ̀ èèyàn láyà .

(src)="7"> Welu , ¿ ngüneduamfulmi kay tati Biblia tami kelluaetew ñi nieal kiñe ayüfal mongen tami ayüwküleal ?
(trg)="7"> Àmọ́ , ǹjẹ́ o mọ̀ pé Bíbélì lè jẹ́ kó o mọ bó o ṣe lè láyọ̀ , kó o sì máa gbé ìgbésí ayé tó nítumọ̀ ?

(src)="8"> Ka ¿ kimürpulmi kay chumngechi papeltuafiel tami afeluwnoaetew ?
(trg)="8"> Tó o bá wá mọ̀ pé àwọn ọ̀nà kan wà tó o lè gbà kà á , tí wàá sì gbádùn ẹ̀ ńkọ́ ?

(src)="9"> ¿ Doy eluwpeafuymi may tami ngüneduamafiel Biblia ñi feypiel ?
(trg)="9"> Ṣé wàá fẹ́ láti gbìyànjú ẹ̀ wò , kó o sì rí ọ̀pọ̀ àǹfààní tó wà nínú kíka Bíbélì ?

(src)="10"> Fentren che eluwlu ñi papeltuafiel tati Biblia , rume ayüfingün .
(trg)="10"> Àwọn kan ti ka Bíbélì , ó sì ti ṣe wọ́n láǹfààní .

(src)="11"> Inaduamnge kiñeke ñi feypiel .
(trg)="11"> Jẹ́ ká gbọ́ ohun tí díẹ̀ lára wọn sọ .

(src)="12"> Esekiel nielu 20 tripantu püle , feypi : “ Kuyfi , iñche felekefun kiñe che reke amulniefilu kiñe auto , welu rakiduamkenolu chew tañi amual .
(trg)="12"> Ezekiel , tó ṣẹ̀ṣẹ̀ lé lọ́mọ ogún [ 20 ] ọdún , sọ pé : “ Tẹ́lẹ̀ , mo dà bí ẹni tó ń wa mọ́tò láìjẹ́ pé ó ní ibi kan lọ́kàn tó fẹ́ lọ .

(src)="13"> Welu ñi papeltufiel Biblia kellukeenew ñi nieal kiñe ayüfal mongen .
(trg)="13"> Ṣùgbọ́n kíka Bíbélì ti jẹ́ kí ìgbésí ayé mi túbọ̀ ní ìtúmọ̀ .

(src)="14"> Ti Biblia niey falinke ngülam ñi inayafiel fill antü ” .
(trg)="14"> Ó ní àwọn ìmọ̀ràn ọlọ́gbọ́n tí mo lè máa lò lójoojúmọ́ . ”

(src)="15"> Kiñe üllcha domo nielu 20 tripantu püle , Frida pingelu , feypi : “ Iñche lladküfemkefun .
(trg)="15"> Frieda , tí òun náà ti lé lọ́mọ ogún [ 20 ] ọdún , sọ pé : “ Tẹ́lẹ̀ , ńṣe ni mo máa kanra lódìlódì .

(src)="16"> Welu ñi papeltufiel Biblia kelluenew ñi ngünewal .
(trg)="16"> Àmọ́ nígbà tí mo bẹ̀rẹ̀ sí í ka Bíbélì , mo tí mọ bí mo ṣe lè kápá rẹ̀ .

(src)="17"> Femngechi doy küme yewkülen kakelu che engu , feymu fewla nien doy weni ” .
(trg)="17"> Ní báyìí , àwọn èèyàn ti ń sún mọ́ mi , mo sì ti láwọn ọ̀rẹ́ tó pọ̀ sí i . ”

(src)="18"> Ti papay Eunice 50 tripantu nielu , feypi ti Biblia mew : “ Kellunieenew ñi doy küme chengeal , tañi elkünual ñi wedake wimtun ” .
(trg)="18"> Obìnrin kan tó ń jẹ́ Eunice tó ti lé lẹ́ni àádọ́ta [ 50 ] ọdún , sọ nípa Bíbélì pé , “ Bíbélì ti ràn mí lọ́wọ́ láti ní ìwà tó dáa . ”

(src)="19"> Tüfachi pu che ka rume fentren che reke , tami papeltufiel Biblia kelluafeymu tami nieal doy ayüwün - ngechi mongen ( Isaías 48 : 17 , 18 ) .
(trg)="19"> Bíi tàwọn tá a sọ̀rọ̀ wọn yìí àti ọ̀kẹ́ àìmọye àwọn míì , kíka Bíbélì lè ran ìwọ náà lọ́wọ́ láti gbádùn ìgbésí ayé rẹ .

(src)="20"> Fillke dungu mu kelluafeymu ta Biblia , kiñeke tüfa : 1 ) küme dullial tami chumal , 2 ) tami nieal kümeke weni , 3 ) tami chaftuafiel ti afeluwün - ngechi dungu , ka 4 ) tami kimürpuafiel ti rüf dungu Chaw Ngünechen mu , tüfa tati doy falin - ngelu .
(trg)="20"> Ọ̀pọ̀ nǹkan ni Bíbélì lè ṣe fún ẹ , lára wọn ni ( 1 ) ṣíṣe ìpinnu tó tọ́ , ( 2 ) yíyan ọ̀rẹ́ tòótọ́ , ( 3 ) fífara da ìdààmú , ( 4 ) èyí tó wá ṣe pàtàkì jù ni pé , wàá kẹ́kọ̀ọ́ òtítọ́ nípa Ọlọ́run .

(src)="21"> Biblia tañi ngülam Chaw Ngünechen mu küpay ka kidu turpu wülkelay wedake ngülam , feymu refalta inalayafimi .
(trg)="21"> Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni gbogbo ìmọ̀ràn tó wà nínú Bíbélì ti wá , torí náà o kò ní kọsẹ̀ tó o bá fi wọ́n sílò .

(src)="22"> Rume fali tami eluwal ñi papeltufiel .
(trg)="22"> Ọlọ́run kò lè fún wa ní ìmọ̀ràn burúkú .

(src)="23"> Feymu tami afeluwnoal ti papeltun mu ka tami ayüwmafiel , ¿ chem kelluafeymu ?
(trg)="24"> Àmọ́ , kí làwọn nǹkan tó máa jẹ́ kó rọrùn fún ẹ láti bẹ̀rẹ̀ , kó o sì gbádùn rẹ̀ ?

# arn/2017006.xml.gz
# yo/2017006.xml.gz


(src)="1"> WÜNEN PAGINA ÑI PENGELNIEEL | CHUMNGECHI DOY KÜMELKAYAFEYMU TAMI PAPELTUFIEL BIBLIA
(trg)="1"> KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ | BÓ O ṢE LÈ RÍ Ẹ̀KỌ́ KỌ́ LÁTINÚ KÍKA BÍBÉLÌ

(src)="2"> ¿ Chumngechi doy ayüwmafimi tami papeltufiel Biblia ka tami doy kelluaetew ?
(trg)="2"> Àwọn ìgbésẹ̀ wo lo lè gbé táá jẹ́ kó o gbádùn Bíbélì kíkà , kó o sì jàǹfààní nínú rẹ̀ ?

(src)="3"> Inaduamnge tüfachi kechu ngülam ñi kellukefiel ta fentren che .
(src)="4"> Pepikange chew tami papeltual .
(trg)="3"> Wo àwọn àbá márùn - ún yìí tó ti ran ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́wọ́ .

(src)="5"> Kintunge chew tami tüngküleal .
(trg)="4"> Jẹ́ kí ibi tó o wà tù ẹ́ lára .

(src)="6"> Mülekilpe chem no rume tami katrütuaetew tami papeltun .
(trg)="5"> Wá ibi tó pa rọ́rọ́ , kó o sì dín ohun tó lè pín ọkàn rẹ níyà kù , kó o lè pọkàn pọ̀ sórí ohun tí ò ń kà .

(src)="7"> Küme pelontule ti mülewe ka füshkülele , fey doy kelluaeymu tami papeltufiel .
(trg)="6"> Ó tún ṣe pàtàkì pé kí ìmọ́lẹ̀ àti afẹ́fẹ́ tó tura wà níbẹ̀ , kí ohun tí ò ń kà lè wọ̀ ẹ́ lọ́kàn .

(src)="8"> Küme rakiduam mu papeltunge .
(trg)="7"> Ní èrò tó tọ́ .

(src)="9"> Tati Biblia taiñ Wenu Chaw mu küpay , feymu tami kelluaetew ti papeltun , müley tami rakiduamal kiñe pichiche reke eluwkülelu ñi kimeltuetew tañi poyen chaw .
(trg)="8"> Ọ̀dọ̀ Baba wa ọ̀run ni Bíbélì ti wá , torí náà kó o lè jàǹfààní nínú rẹ̀ , á dára kó o ní ìwà ìrẹ̀lẹ̀ bí ọmọdé tó fẹ́ kẹ́kọ̀ọ́ látọ̀dọ̀ òbí tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ .

(src)="10"> Feymu tami kimeltuaetew ta Chaw Ngünechen , kiñe pülekünunge chem weda rakiduam tami niefel ti Biblia mu ( Salmo 25 : 4 ) .
(trg)="9"> Tó o bá ti ní èrò òdì nípa Bíbélì tẹ́lẹ̀ , o ní láti gbé èrò náà tì sẹ́gbẹ̀ẹ́ kan , kí Ọlọ́run lè kọ́ ẹ . ​ — Sáàmù 25 : 4 .

(src)="11"> Wüne ngillatunge .
(trg)="10"> Kọ́kọ́ Gbàdúrà .

(src)="12"> Chaw Ngünechen ñi rakiduam müley ti Biblia mew , feymu duamnieiñ tañi kellun taiñ adümnieafiel .
(trg)="11"> Èrò Ọlọ́run ló wà nínú Bíbélì , ìdí nìyẹn tá a fi nílò ìrànlọ́wọ́ rẹ̀ ká lè lóye ohun tí à ń kà .

(src)="13"> Kidu ‘ eluafi tañi newen tüfey engün tañi ngillatuetew ’ ( Luka 11 : 13 ) .
(trg)="12"> Ọlọ́run ti ṣèlérí láti “ fi ẹ̀mí mímọ́ fún àwọn tí ń béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ . ”

(src)="14"> Tüfa kelluaeymu tami kimürpual chumngechi ñi rakiduamken ta Chaw Ngünechen .
(trg)="13"> Ẹ̀mí mímọ́ yìí lè mú kó o mọ èrò Ọlọ́run lórí àwọn nǹkan .

(src)="15"> Rupalu chi antü mu , kelluaeymu tami kimafiel “ Ngünechen tañi kimngekenofelchi dungu kütu ” ( 1 Korintio 2 : 10 ) .
(trg)="14"> Tó bá yá , ẹ̀mí mímọ́ á ṣí ọkàn rẹ payá láti mọ “ àwọn ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run . ” ​ — 1 Kọ́ríńtì 2 : 10 .

(src)="16"> Re papeltukawlayaymi müten .
(trg)="15"> Kà á lọ́nà tó fi máa yé ẹ .

(src)="17"> Eluwlayaymi tami fentren papeltual müten .
(trg)="16"> Má kàn máa ka Bíbélì lọ gbuurugbu .

(src)="18"> Rakiduamnienge tami papeltun mu .
(trg)="17"> Máa dánu dúró kó o lè ronú lórí ohun tó o kà .

(src)="19"> Ramtuwnge : “ Tati che ñi papeltupefiel , ¿ chumngey tañi femngen ?
(trg)="18"> Bí ara rẹ láwọn ìbéèrè bíi : ‘ Ẹ̀kọ́ wo ni mo kọ́ lára ẹni tí mò ń kà nípa rẹ̀ yìí ?

(src)="20"> ¿ Chumngechi inayafun tüfa tañi mongen mu ? ” .
(trg)="19"> Báwo ni mo ṣe lè fi ẹ̀kọ́ náà sílò nígbèésí ayé mi ? ’

(src)="21"> Rakiduamnge chem tami küpa diturpual .
(trg)="20"> Ní àfojúsùn kan .

(src)="22"> Tami papeltun mu , kintunge chem tami kelluaetew ti mongen mu , femngechi kümeke kimeltun entuaymi .
(trg)="21"> Kí Bíbélì kíkà tó lè ṣe ẹ́ láǹfààní , o yẹ kó o ní ohun kan lọ́kàn tó o fẹ́ kẹ́kọ̀ọ́ nípa rẹ̀ tó máa wúlò fún ẹ nígbèésí ayé .

(src)="23"> Eluwafuymi tami doy kimal Chaw Ngünechen mu , doy küme chengeal , doy küme fütangeal kam doy küme domongeal .
(trg)="22"> O lè fi ṣe àfojúsùn rẹ pé : ‘ Mo fẹ́ kẹ́kọ̀ọ́ sí i nípa Ọlọ́run fúnra rẹ̀ . ’

(src)="24"> Fey dullinge ( ngümintunge ) kiñe trokiñ Biblia mu tami kelluaetew tüfachi dungu mew .
(trg)="24"> Lẹ́yìn náà , yan ẹsẹ Bíbélì tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ lórí kókó náà .

(src)="25"> *
(trg)="25"> *

(src)="26"> Tüfachi kechu ngülam kelluaeymu tami eluwal ti papeltun mu .
(trg)="26"> Àwọn àbá márùn - ún tá a ti jíròrò yìí máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti bẹ̀rẹ̀ sí i kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì .

(src)="27"> Welu , ¿ chumngechi doy ayüwmayafimi ti papeltun ?
(trg)="27"> Àmọ́ , báwo lo ṣe lè mú kí Bíbélì kíkà náà gbádùn mọ́ ẹ ?

(src)="28"> Ti küpachi trokiñ mu müley kiñeke ngülam .
(trg)="28"> Àpilẹ̀kọ tó kàn máa ṣèrànwọ́ .

(src)="29"> Newe kimnolmi chem trokiñ Biblia mu tami kelluaetew tüfachi dungu mew , pu Dungukelu Iney Ngen Jewba ayüwünkechi kelluaeymu .
(trg)="29"> Tí o kò bá mọ ẹsẹ Bíbélì tó o máa kà lórí kókó kàn , inú àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà máa dùn láti ràn ẹ́ lọ́wọ́ .

(src)="30"> Matu papeltulayaymi
(trg)="30"> Fara balẹ̀ , kó o má sì kánjú

(src)="31"> Eluwnge tami papeltufiel mu tami peniefiel reke
(trg)="31"> Jẹ́ kí ohun tí ò ń kà jinlẹ̀ lọ́kàn rẹ ​ — fọkàn yàwòrán pé o wà níbẹ̀

(src)="32"> Inaduamnge chem ñi nüwkülen tüfachi versikulo mu
(trg)="32"> Gbìyànjú láti wo bí àwọn ẹsẹ náà ṣe bára mu

(src)="33"> Nentunge falinke kimeltun tami papeltufiel mu
(trg)="33"> Wo ẹ̀kọ́ tó wà nínú ibi tó o kà

# arn/2017007.xml.gz
# yo/2017007.xml.gz


(src)="1"> WÜNEN PAGINA ÑI PENGELNIEEL | CHUMNGECHI DOY KÜMELKAYAFEYMU TAMI PAPELTUFIEL BIBLIA
(trg)="1"> KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ | BÓ O ṢE LÈ RÍ Ẹ̀KỌ́ KỌ́ LÁTINÚ KÍKA BÍBÉLÌ

(src)="2"> ¿ Chumngechi trokikefimi tami papeltufiel Biblia ?
(trg)="2"> Ṣé kíka Bíbélì máa ń gbádùn mọ́ni ?

(src)="3"> ¿ Afeluwkeymi ?
(trg)="3"> Àǹfààní wo lo sì máa rí níbẹ̀ ?

(src)="4"> Kam ¿ füshküduamelkeeymew ?
(trg)="4"> Ìdáhùn àwọn ìbéèrè yìí sinmi lórí ọ̀nà tí ò ń gbà ka Bíbélì .

(src)="5"> Chumngechi tami papeltufiel kelluaeymu tami küme duamal ka tami doy ayüwal ti papeltun mu .
(trg)="5"> Jẹ́ ká wo ohun tó o lè ṣe láti mú kí Bíbélì máa wù ẹ́ kà , kó o sì gbádùn rẹ̀ .

(src)="6"> Inaduamaiñ chem chumal .
(src)="7"> Kintunge kiñe Biblia manelfalngelu ka adümfalngelu .
(trg)="6"> Lo Bíbélì tó dáa , tí ọ̀rọ̀ inú rẹ̀ sì bágbà mu .

(src)="8"> Dullilmi kiñe Biblia , adümfalngenolu kam wirintukungenolu chumngechi tati pu che ñi dunguken famülke mu , fey afeluwafuymi tami papeltufiel .
(trg)="7"> Tó o bá ka Bíbélì tí àwọn ọ̀rọ̀ inú rẹ̀ ṣòro láti lóye tàbí tí kò bágbà mu , oò ní gbádùn ohun tí ò ń kà nínú rẹ̀ .

(src)="9"> Feymu kintunge kiñe Biblia adümfalngelu , fey ñi puwal tami piwke mu .
(trg)="8"> Torí náà , Bíbélì tó máa tètè yé ẹ táwọn ọ̀rọ̀ inú rẹ̀ sì máa wọ̀ ẹ́ lọ́kàn ni kó o lò .

(src)="10"> Welu ka müley ñi manelfalngeal ka ñi küme rulpadungungeel .
(trg)="9"> Lẹ́sẹ̀ kan náà , ó gbọ́dọ̀ jẹ́ Bíbélì tí wọ́n fara balẹ̀ túmọ̀ , tí ìtúmọ̀ rẹ̀ sì péye .

(src)="11"> *
(trg)="10"> *

(src)="12"> Fillke elektroniko chemkün kelluafeymu .
(trg)="11"> Lo ohun èlò ìgbàlódé .

(src)="13"> Famülke mu tati Biblia müley papel mu , welu kafey müleafuy tami elektroniko chemkün mu .
(trg)="12"> Lóde òní , kì í ṣe orí ìwé nìkan la ti lè rí Bíbélì kà , a tún lè wà á jáde sórí fóònù , tablet tàbí kọ̀ǹpútà , ká sì máa kà á látibẹ̀ .

(src)="14"> Kiñeke Biblia papeltungeafuy internet mu , kam entungeafuy ñi papeltungeal komputador mu , tablet kam celular mew .
(trg)="13"> Àwọn Bíbélì orí ẹ̀rọ kan tiẹ̀ wà tó tún máa fún ẹ láǹfààní láti wo ẹsẹ Bíbélì kan tàbí kókó ọ̀rọ̀ kan nínú àwọn ìtúmọ̀ Bíbélì míì kó o lè fi wọ́n wéra .

(src)="15"> Kiñeke nieyngün fillke kellun ñi inaduamal kakelu versikulo nüwkülelu kam trürümafiel kakelu rulpadungungeelchi Biblia .
(trg)="14"> Tó bá jẹ́ pé èyí tó o lè tẹ́tí sí ló rọ̀ ẹ́ lọ́rùn , Bíbélì tí wọ́n ti kà sílẹ̀ tún wà tó o lè máa gbọ́ .

(src)="16"> Newe ayünolmi tami papeltual , fey allkütuafuymi ti Biblia .
(src)="17"> Fentren che ayükey ñi allkütuafiel mikro mu amulelu , küchatumekelu kam kangelu küdaw mu ñi femngekeel .
(trg)="15"> Ọ̀pọ̀ èèyàn gbádùn kí wọ́n máa tẹ́tí sí Bíbélì tí wọ́n ti kà sílẹ̀ nígbà tí wọ́n bá wà nínú mọ́tò , tí wọ́n ń fọṣọ , tàbí tí wọ́n ń ṣe àwọn nǹkan míì tó gbà wọ́n láyè láti máa fetí sílẹ̀ .

(src)="18"> Tüfachi kellun mu dulliafuymi chuchi tami doy ayüfiel .
(trg)="16"> Oò ṣe gbìyànjú èyí tó máa rọrùn fún ẹ nínú àwọn àbá yìí ?

(src)="19"> Allmalltunge ti fillke kellun tami chillkatuafiel ti Biblia .
(trg)="17"> Lo ohun tó o lè fi kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì .

(src)="20"> Tüfa kelluaeymu tami entual doy kümeke kimeltun tami papeltun mu .
(trg)="18"> Àwọn ohun tó o lè fi kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì yìí máa jẹ́ kó o túbọ̀ jàǹfààní nínú kíka Bíbélì .