# aed/102007361.xml.gz
# yo/102007361.xml.gz


(src)="1"> MARINA y Jorge son una pareja alegre y feliz .
(trg)="2"> ỌLỌ́YÀYÀ èèyàn tí inú wọn sì máa ń dùn ni Fẹ́mi àti ìyàwó rẹ̀ , Dúpẹ́ .

(src)="2"> * Tienen un hijo de tres años de edad , un niño saludable y despierto al que cuidan con especial esmero .
(trg)="3"> Ọmọ wọn ọkùnrin ti pé ọmọ ọdún mẹ́ta , ọmọ náà já fáfá , ara rẹ̀ sì le dáadáa .
(trg)="4"> * Wọn ò fi ìtọ́jú jẹ ẹ́ níyà rárá .

(src)="3"> En el mundo de hoy , esa no es una tarea fácil , dados los múltiples deberes y preocupaciones que entraña .
(trg)="5"> Ìyẹn kì í ṣe ohun tó rọrùn nínú ayé tá à ń gbé yìí ṣáá o .
(trg)="6"> Béèyàn ṣe ń já sókè lá á máa já sódò , ojúṣe ibẹ̀ ò sì kéré .

(src)="4"> ¡ Son tantas las cosas que hay que enseñar a los hijos !
(trg)="7"> Ọ̀pọ̀ nǹkan ni òbí gbọ́dọ̀ fi kọ́ ọmọ !

(src)="5"> Este matrimonio está particularmente preocupado por proteger a su pequeño del abuso sexual .
(trg)="8"> Èyí tó gba Fẹ́mi àti Dúpẹ́ lọ́kàn jù lọ lára ojúṣe wọn gẹ́gẹ́ bí òbí rèé : Wọ́n fẹ́ láti dáàbò bo ọmọ wọn lọ́wọ́ àwọn tó ń bọ́mọdé ṣèṣekúṣe .

(src)="6"> ¿ Por qué razón ?
(trg)="9"> Báwo ló ṣe jẹ́ bẹ́ẹ̀ ?

(src)="7"> “ Mi padre era un hombre frío y violento que se emborrachaba con mucha frecuencia — relata Marina — .
(trg)="10"> Dúpẹ́ tó jẹ́ ìyá ọmọ náà sọ pé : “ Ọ̀dájú ni bàbá mi , ọ̀mùtípara ni , ó sì máa ń tètè fara ya .

(src)="8"> Me daba unas palizas terribles y abusaba de mí y de mis hermanas . ”
(trg)="11"> Ó máa ń lù mí játijàti , ó sì máa ń bá èmi àtàwọn àbúrò mi ṣèṣekúṣe . ”

(src)="9"> * Para nadie es un secreto que este tipo de abuso deja hondas cicatrices emocionales .
(trg)="12"> * Àwọn ọ̀mọ̀ràn níbi gbogbo gbà pé irú ìṣekúṣe bẹ́ẹ̀ lè múni banú jẹ́ lọ́nà kíkorò .

(src)="10"> Es lógico , pues , que Marina , al igual que su esposo , esté decidida a proteger a su hijo .
(trg)="13"> Abájọ tí Dúpẹ́ fi pinnu pé òun á dáàbò bo ọmọ òun !
(trg)="14"> Ọkọ ẹ̀ náà sì ṣe tán láti bá a fọwọ́ sowọ́ pọ̀ .

(src)="11"> A muchos padres les inquieta la situación , y tal vez usted sea uno de ellos .
(trg)="15"> Bíbá tí wọ́n ń bá àwọn ọmọdé ṣèṣekúṣe ti wá di ohun tí ọ̀pọ̀ òbí ń ṣàníyàn lé lórí báyìí .

(src)="12"> Es posible que no haya padecido en carne propia esta clase de agresión y sus secuelas como Marina y Jorge , pero seguramente ha oído informes espantosos sobre lo común que es esta aberración .
(trg)="16"> Bóyá ìwọ náà sì wà lára wọn .
(trg)="17"> Wọ́n lè má tíì bá ẹ ṣèṣekúṣe rí bíi ti Dúpẹ́ , ìyàwó Fẹ́mi , kó o má sì mọ bó ṣe máa ń rí lára .

(src)="13"> Por todo el mundo , los padres sienten horror al enterarse de lo que les está sucediendo a los niños de su propia comunidad .
(trg)="19"> Kárí ayé lọkàn àwọn òbí tí ò fọ̀rọ̀ ọmọ wọn ṣeré kì í ti í balẹ̀ bí wọ́n ṣe ń gbọ́ nípa nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ sáwọn ọmọdé níbi tí wọ́n ń gbé .

(src)="14"> No sorprende que cierto especialista en el tema calificara la magnitud del abuso infantil como “ uno de los descubrimientos más desmoralizadores de nuestros tiempos ” .
(trg)="20"> Abájọ , ẹnì kan tí iṣẹ́ ìwádìí rẹ̀ máa ń dá lórí fífi ìbálòpọ̀ fìtínà ẹni sọ nípa ibi tí bíbọ́mọdé ṣèṣekúṣe gogò dé , ó ní “ ó jẹ́ ọ̀kan lára ohun tí ń kó ìrẹ̀wẹ̀sì báni jù lọ tó tíì ṣẹlẹ̀ rí lákòókò tá à ń gbé yìí . ”
(trg)="21"> Ìròyìn tí ń bani nínú jẹ́ gbáà mà nìyẹn o !

(src)="15"> Malas noticias , sin duda ; pero ¿ sorprendentes ?
(trg)="22"> Àmọ́ , ṣó yẹ kírú àwọn nǹkan bí èyí máa yani lẹ́nu ?

(src)="16"> No para quienes estudian la Biblia .
(trg)="23"> Kò jẹ́ jẹ́ ohun ìyàlẹ́nu fáwọn tó ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì .

(src)="17"> La Palabra de Dios predijo que viviríamos en un período difícil llamado “ los últimos días ” , un tiempo en que predominaría el comportamiento ‘ feroz ’ y habría hombres “ amadores de sí mismos ” y sin “ cariño natural ” .
(trg)="24"> Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ṣàlàyé pé à ń gbé ní àkókò ìdààmú tí Bíbélì pè ní “ àwọn ọjọ́ ìkẹyìn , ” tó kún fún ìwà “ òǹrorò , ” nínú èyí táwọn èèyàn á ti jẹ́ “ olùfẹ́ ara wọn ” tí wọ́n á sì jẹ́ “ aláìní ìfẹ́ni àdánidá . ” — 2 Tímótì 3 : 1 - 5 .

(src)="18"> El abuso sexual es un tema que intimida ; de hecho , nos abruma la perversidad de quienes buscan niños para aprovecharse de ellos .
(trg)="25"> Ìṣòro tó ń muni lómi gbáà lọ̀rọ̀ ìbọ́mọdé - ṣèṣekúṣe .
(trg)="26"> Ìwà tó burú jáì ni fáwọn èèyàn kan láti máa wá àwọn ọmọdé tí wọ́n á bá ṣèṣekúṣe kiri .

(src)="19"> Ahora bien , ¿ son impotentes los padres ante este problema ?
(trg)="28"> Ṣé a wá lè sọ pé ìṣòro yìí ti kọjá èyí ti apá àwọn òbí lè ká ?

(src)="20"> ¿ O existen medidas preventivas que puedan adoptar ?
(trg)="29"> Àbí àwọn ohun tó bọ́gbọ́n mu kan wà táwọn òbí lè ṣe kí wọ́n bàa lè dáàbò bo àwọn ọmọ wọn ?

(src)="21"> Los siguientes artículos abordarán estas cuestiones .
(trg)="30"> Àwọn àpilẹ̀kọ tó kàn á tú iṣu ìdáhùn sáwọn ìbéèrè yìí désàlẹ̀ ìkòkò .

(src)="22"> Se han cambiado los nombres .
(trg)="32"> A ti yí àwọn orúkọ tó wà nínú ọ̀wọ́ àpilẹ̀kọ yìí padà .

(src)="23"> Comete abuso sexual de menores el adulto que utiliza a un niño para satisfacer su apetito carnal .
(trg)="33"> Kí ọkùnrin tàbí obìnrin àgbàlagbà máa lo ọmọdé láti fi tẹ́ ìfẹ́ ara rẹ̀ fún ìbálòpọ̀ lọ́rùn ló ń jẹ́ bíbá ọmọdé ṣèṣekúṣe .

(src)="24"> El abuso implica generalmente actos que la Biblia llama fornicación ( por·néi·a ) , entre ellos acariciar los órganos genitales , realizar el coito y practicar el sexo oral o anal .
(trg)="35"> Lára àwọn nǹkan tó túmọ̀ sí por·neiʹa ni fífọwọ́ pa ẹ̀yà ìbálòpọ̀ , bíbáni lò pọ̀ , fífi ẹnu pọ́n ẹ̀yà ìbálòpọ̀ lá , tàbí kí ọkùnrin máa ki nǹkan ọmọkùnrin rẹ̀ bọnú ihò ìdí obìnrin tàbí ọkùnrin bíi tiẹ̀ .

(src)="25"> Otros actos abusivos — como acariciar los pechos , hacer proposiciones deshonestas explícitas , mostrar pornografía , gozar espiando a otros ( voyerismo ) y mostrar los genitales ( exhibicionismo ) — pueden constituir “ conducta relajada ” o “ inmundicia con avidez ” , prácticas condenadas por la Biblia .
(trg)="36"> Àwọn nǹkan míì tó jẹ mọ́ ìṣekúṣe , bíi fífọwọ́ pani lọ́yàn , fífi ìṣekúṣe lọni , fífi àwòrán oníhòòhò han ọmọdé , yíyọjú wo ẹni tó bọ́ra sílẹ̀ tàbí yíyọjú wo àwọn tó ń bára wọn lò pọ̀ àti ṣíṣí ara sílẹ̀ níbi tí kò yẹ , lè já sí ohun tí Bíbélì dẹ́bi fún tó sì pè ní “ ìwà àìníjàánu ” tàbí fífi “ ìwà ìwọra hu onírúurú ìwà àìmọ́ gbogbo . ” — Gálátíà 5 : 19 - 21 ; Éfésù 4 : 19 .

# aed/102007362.xml.gz
# yo/102007362.xml.gz


(src)="1"> EL ABUSO sexual de menores no es en absoluto un tema agradable ; dan escalofríos de solo pensarlo , sobre todo a los padres .
(trg)="2"> Ọ̀PỌ̀ lára wa ni kì í fẹ́ pẹ́ lórí ọ̀rọ̀ tó bá ti jẹ mọ́ bíbọ́mọdé ṣèṣekúṣe .

(src)="2"> Sin embargo , es una cruda y espantosa realidad del mundo actual con trágicas consecuencias para los niños .
(trg)="3"> Àwọn òbí kì í tiẹ̀ fẹ́ gbọ́ ohun tó jọ ọ́ nítorí pé ṣe ló máa ń bí wọn nínú !

(src)="3"> ¿ Merece la pena hablar de ello ?
(trg)="5"> Bó bá rí bẹ́ẹ̀ , ṣó wá yẹ ni ohun téèyàn ń gbé yẹ̀ wò ?

(src)="4"> Pues bien , ¿ cuánto estaría dispuesto a pagar por la seguridad de sus hijos ?
(trg)="8"> Ohun tó o bá sì mọ̀ nípa ẹ̀ á ràn ẹ́ lọ́wọ́ gidigidi láti mú kí ewu fo àwọn ọmọ ẹ dá .

(src)="5"> Conocer algo de las amargas verdades sobre el abuso es un precio ínfimo comparado con las ventajas que puede reportarle .
(trg)="10"> Ó ṣe kò ṣe , o ṣì lágbára tó ju tọmọ ẹ lọ lórí ọ̀ràn náà , agbára tó jẹ́ pé lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún lọmọ ẹ tó máa nírú ẹ̀ .

(src)="6"> No deje que esta plaga lo acobarde .
(trg)="11"> Látìgbà tó o ti dáyé , ọ̀pọ̀ ìmọ̀ , ìrírí àti ọgbọ́n lo ti ní .

(src)="7"> Al menos , usted posee facultades que sus hijos no tienen y que les llevará años — o hasta décadas — desarrollar .
(trg)="12"> Àwọn ohun tó o sì nílò láti ṣàṣeyọrí náà nìyẹn .

(src)="8"> Con la edad ha adquirido un inmenso caudal de conocimientos , experiencia y sabiduría .
(trg)="13"> Ẹnu pé kó o lò wọ́n láti dáàbò bo ọmọ ẹ ló kù .

(src)="9"> La clave está en reforzar dichas facultades y utilizarlas para proteger a sus hijos .
(trg)="14"> Ní báyìí , a óò jíròrò àwọn ohun mẹ́ta tí gbogbo òbí lè ṣe sí ọ̀ràn náà .

(src)="10"> A continuación analizaremos tres medidas esenciales que todos los padres pueden adoptar , a saber : 1 ) convertirse en la primera línea de defensa contra el abuso , 2 ) instruir a los hijos de forma adecuada sobre el tema y 3 ) enseñarles acciones de protección básicas .
(trg)="15"> Àwọn rèé : ( 1 ) Ìwọ ni kó o jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tọ́mọ ẹ á lè rí sá tọ̀ , ( 2 ) jẹ́ káwọn ọmọ ẹ mọ gbogbo ohun tó yẹ kí wọ́n mọ̀ nípa ìbọ́mọdé - ṣèṣekúṣe , àti ( 3 ) kọ́ àwọn ọmọ ẹ lóhun tí wọ́n lè fi gbara wọn sílẹ̀ .
(trg)="16"> Ṣé Ìwọ Lẹni Àkọ́kọ́ Tọ́mọ Ẹ Lè Rí Sá Tọ̀ ?

(src)="11"> La responsabilidad de proteger a los hijos recae principalmente en los padres , no en los hijos ; de ahí que sean ellos quienes deban educarse primero .
(trg)="18"> Nítorí náà , àwọn òbí gan - an ló yẹ kí wọ́n kọ́kọ́ mọ ohun tó yẹ ní ṣíṣe , lẹ́yìn náà lọ̀rọ̀ á tó wá kan àwọn ọmọ .

(src)="12"> Hay cosas que usted necesita saber , como por ejemplo , quiénes abusan de los niños y qué tácticas siguen .
(trg)="19"> Bó o bá jẹ́ òbí , àwọn ohun díẹ̀ wà tó yẹ kó o mọ̀ nípa ìbọ́mọdé ṣèṣekúṣe .

(src)="13"> Muchos se imaginan que los abusadores son extraños que acechan a los niños en las sombras para raptarlos y violarlos .
(trg)="21"> Èrò àwọn òbí nípa àwọn abọ́mọdé - ṣèṣekúṣe ni pé wọ́n sábà máa ń jẹ́ ẹni táwọn ọmọdé ò mọ̀ rí ṣùgbọ́n tí wọ́n á fòru bojú , tí wọ́n á sì yọ́ kẹ́lẹ́ wọlé láti wá jí àwọn ọmọdé gbé kí wọ́n lè lọ fipá bá wọn lò pọ̀ .

(src)="14"> Aunque sabemos por los medios de comunicación que estos monstruos sí existen , son relativamente raros .
(trg)="22"> Àwọn erìkìnà tó bá àpèjúwe yìí mu wà ní tòótọ́ .

(src)="15"> En un 90 % de los casos , el agresor es una persona que el niño conoce y en quien confía .
(trg)="23"> A sì sábà máa ń gbọ́ nípa wọn nínú ìròyìn .
(trg)="24"> Àmọ́ , irú wọn ò fi bẹ́ẹ̀ wọ́pọ̀ .

(src)="16"> Naturalmente , cuesta creer que un vecino , un maestro , un médico , un entrenador o un familiar afables puedan mirar con lujuria a su hijo .
(trg)="25"> Nínú gbogbo abọ́mọdé - ṣèṣekúṣe mẹ́wàá , mẹ́sàn - án ló sábà máa ń jẹ́ ẹni tọ́mọ náà mọ̀ dáadáa tó sì fọkàn tán .

(src)="17"> Y no hay razón para empezar a desconfiar de todo el mundo , pues la mayoría de la gente no hace algo semejante .
(trg)="26"> Ká sòótọ́ , kò sẹ́ni táá fẹ́ gbà gbọ́ pé aládùúgbò tó kóni mọ́ra , olùkọ́ , òṣìṣẹ́ ìlera , olùdánilẹ́kọ̀ọ́ , tàbí ìbátan òun lè máa rokàn ìbálòpọ̀ sọ́mọ òun .

(src)="18"> Aun así , si quiere protegerlo , es preciso que conozca los métodos de que se vale el abusador típico ( véase el recuadro de la página 6 ) .
(trg)="29"> Síbẹ̀ náà , o lè dáàbò bo ọmọ rẹ bí ìwọ fúnra rẹ bá mọ ọgbọ́n táwọn tó ń bọ́mọdé ṣèṣekúṣe ń dá . — Wo àpótí tó wà lójú ìwé 6 .

(src)="19"> Conocer sus tácticas lo preparará mejor para convertirse en la primera línea de defensa .
(trg)="30"> Bí ìwọ tó o jẹ́ òbí bá mọ ọgbọ́n àlùmọ̀kọ́rọ́yí tí wọ́n ń lò , wàá lè jẹ́ ẹni àkọ́kọ́ tọ́mọ ẹ á lè máa rí sá tọ̀ .

(src)="20"> Supongamos que alguien que parece interesarse más por los niños que por los adultos se muestra especialmente atento con su hijo , le hace regalos , se ofrece a cuidarlo en su ausencia sin cobrar o a llevarlo de excursión .
(src)="21"> ¿ Qué hará ?
(trg)="31"> Bí àpẹẹrẹ , bí ẹnì kan tó fẹ́ràn láti máa wà pẹ̀lú àwọn ọmọdé ju àwọn àgbà lọ bá kúndùn àti máa wà pẹ̀lú ọmọ ẹ , tó ń ra ẹ̀bùn fún un , tàbí tó sọ pé òun á máa bá ẹ bójú tó o , tó sì máa ń dá mú un jáde , kí ni wàá ṣe ?

(src)="22"> ¿ Concluir enseguida que es un pervertido ?
(trg)="32"> Ṣé kíá lo ti máa gbà pé abọ́mọdé - ṣèṣekúṣe nirú ẹni bẹ́ẹ̀ ?

(src)="23"> No .
(trg)="33"> Ó tì o .

(src)="24"> No se precipite a sacar conclusiones , puede ser que las acciones de dicha persona sean inocentes .
(trg)="34"> Má ṣe jẹ́ kó yá ẹ jù láti ronú pé bónítọ̀hún ṣe jẹ́ nìyẹn .

(src)="25"> De todos modos , hay que estar sobre aviso .
(trg)="35"> Ó lè jẹ́ pé ó kàn ń ṣe tiẹ̀ lásán ni o .

(src)="26"> “ Cualquiera que es inexperto pone fe en toda palabra — dice la Biblia — , pero el sagaz considera sus pasos . ”
(trg)="37"> Bíbélì ṣáà sọ pé : “ Ẹnikẹ́ni tí ó jẹ́ aláìní ìrírí ń ní ìgbàgbọ́ nínú gbogbo ọ̀rọ̀ , ṣùgbọ́n afọgbọ́nhùwà máa ń ronú nípa àwọn ìṣísẹ̀ ara rẹ̀ . ” — Òwe 14 : 15 .

(src)="27"> Recuerde que todo ofrecimiento que parezca demasiado bueno para ser cierto seguramente lo es .
(trg)="38"> Rántí pé , ìwọ̀nba díẹ̀ lohun tó dáa dùn mọ o .

(src)="28"> Indague a fondo los antecedentes de cualquiera que se ofrezca a pasar tiempo a solas con su hijo .
(trg)="39"> Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ láti máa dá wà pẹ̀lú ọmọ ẹ ṣáá , rí i pó o mọ onítọ̀hún dáadáa .

(src)="29"> Hágale saber que usted puede aparecer en cualquier momento para comprobar que todo esté bien .
(trg)="40"> Jẹ́ kírú ẹni bẹ́ẹ̀ mọ̀ pé ìgbàkigbà lo lè wá bẹ ọmọ ẹ wò .

(src)="30"> Alicia y Fernando , un matrimonio joven con tres hijos , son muy cautelosos a la hora de dejar a uno de ellos solo con un adulto .
(trg)="41"> Òbí tó ṣì ń tọ́ ọmọkùnrin mẹ́ta lọ́wọ́ ni Títí àti Dàmọ́lá , àmọ́ ọwọ́ kékeré kọ́ ni wọ́n fi mú ọ̀ràn jíjẹ́ kí ọmọ wọn máa dá wà pẹ̀lú àgbàlagbà .

(src)="31"> Cuando uno de los niños tomaba clases de música en su casa , Alicia le dijo al profesor : “ Estaré entrando y saliendo de la habitación mientras usted esté aquí ” .
(trg)="42"> Nígbà tí ẹnì kan wá ń kọ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọ wọn ọkùnrin lórin nílé , Melissa sọ fún olùkọ́ náà pé : “ Mi ò ní yé máa wá wò yín títí tí wàá fi ṣe tán . ”

(src)="32"> Tal vigilancia pudiera parecer exagerada , pero estos padres prefieren prevenir que lamentar .
(trg)="43"> Ó lè dà bíi pé àṣejù ti wọ ọ̀ràn náà , àmọ́ ṣe kò dáa báwọn òbí yìí ṣe fi àbámọ̀ ṣáájú ọ̀ràn .

(src)="33"> Participe decididamente en las actividades de su hijo , conozca a sus amigos , revise sus deberes escolares ; si se proyecta una excursión , averigüe todos los detalles .
(trg)="44"> Má ṣe dá ọmọ ẹ dá gbogbo ohun tó bá ń ṣe , mọ àwọn tó ń bá ṣọ̀rẹ́ , máa bá a dá sí iṣẹ́ tí wọ́n bá gbé fún un nílé ìwé .

(src)="34"> Un profesional de la salud mental que durante treinta y tres años atendió casos de abuso sexual comenta que un gran número de ellos pudieron haberse evitado con la sola vigilancia de los padres , y cita estas palabras de un convicto por abuso : “ Los padres nos sirven a sus hijos en bandeja de plata .
(trg)="46"> Ògbógi kan tó jẹ́ oníṣègùn ọpọlọ tó sì ti fi ọdún mẹ́tàlélọ́gbọ̀n tọ́jú onírúurú èèyàn tí wọ́n bá ṣèṣekúṣe sọ pé àìmọye irú ìṣekúṣe bẹ́ẹ̀ ni kì bá tí wáyé ká sọ pé àwọn òbí wà lójú fò .

(src)="35"> [ . . . ]
(trg)="47"> Ó ní abọ́mọdé - ṣèṣekúṣe kan tí wọ́n ti dájọ́ fún sọ pé : “ Àwọn òbí gan - an ni wọ́n ń fọwọ́ ara wọn fa àwọn ọmọ wọn lé wa lọ́wọ́ . . . .

(src)="36"> ¡ Me lo ponían tan fácil ! ” .
(trg)="48"> Àwọn gan - an ni wọ́n mú kó rọrùn fún mi . ”

(src)="37"> Recuerde que la mayoría de los abusadores buscan presas fáciles , y una forma de evitar que su hijo lo sea es implicarse de lleno en su vida .
(trg)="49"> Má ṣe gbà gbé pé àwọn ọmọ tó bá rọrùn láti bá ṣèṣekúṣe lọ̀pọ̀ lára wọn máa ń wá kiri .

(src)="38"> Otra manera de ser la primera línea de defensa es saber escuchar .
(trg)="51"> Ọ̀nà míì tó o lè gbà mú kó rọrùn fọ́mọ ẹ láti rí ẹ bí ẹni tó lè máa sá tọ̀ ni pé kó o máa tẹ́tí sí i dáadáa .

(src)="39"> Los niños casi nunca hablan abiertamente del tema por vergüenza o por temor a la reacción .
(trg)="52"> Àwọn ọmọdé kì í sábà sọ bí ẹnikẹ́ni bá bá wọn ṣèṣekúṣe ; ojú máa ń tì wọ́n jù , ẹ̀rù ohun táwọn ẹlòmíì á sọ sì máa ń bà wọ́n .

(src)="40"> Así que escuche con detenimiento .
(src)="41"> Preste atención aun al más leve indicio .
(trg)="53"> Nítorí náà , fetí sílẹ̀ dáadáa , ì báà tiẹ̀ jẹ́ àmì kékeré kan lo rí .

(src)="42"> * Si le preocupa algo que su hijo dice , conserve la calma y hágale preguntas para que se abra .
(trg)="54"> * Bí ọmọ ẹ bá sọ ohun kan tí kò fi ẹ́ lọ́kàn balẹ̀ , fara balẹ̀ fi ìbéèrè wá a lẹ́nu wò .

(src)="43"> * Si él no quiere que venga cierto niñero o niñera , pregúntele por qué .
(trg)="55"> * Bó bá sọ pé òun ò fẹ́ kẹ́ni tẹ́ ẹ ni kó máa wá dúró ti òun nílé wá mọ́ , bi í pé kí nìdí tó fi sọ bẹ́ẹ̀ .

(src)="44"> Si le cuenta que un adulto juega con él a cosas raras , pregúntele : “ ¿ Qué clase de cosas ?
(trg)="56"> Bó bá sọ pé eré tí àgbàlagbà kan ń bá òun ṣe ò ye òun tó , bi í pé : “ Irú eré wo leré náà ?

(src)="45"> ¿ Qué te hace ? ” .
(trg)="57"> Kí lonítọ̀hún ṣe gan - an ? ”

(src)="46"> Si se queja de que alguien le hizo cosquillas , pregúntele : “ ¿ Dónde te hizo cosquillas ? ” .
(trg)="58"> Bó bá sọ pé ẹnì kan fọwọ́ kan òun , bi í pé , “ Ibo ló fọwọ́ kàn lára ẹ ? ”

(src)="47"> No reste importancia a sus respuestas .
(trg)="59"> Má máa tètè fojú kò - tó - nǹkan wo ìdáhùn tọ́mọ ẹ bá fún ẹ .

(src)="48"> Los abusadores les dicen a los niños que nadie les creerá , y eso es lo que suele ocurrir .
(trg)="60"> Àwọn tó ń bọ́mọdé ṣèṣekúṣe sábà máa ń sọ fáwọn ọmọ náà pé kò sẹ́ni tó máa gba ohun tí wọ́n bá sọ gbọ́ ; lọ́pọ̀ ìgbà sì rèé , ohun tó máa ń ṣẹlẹ̀ gan - an nìyẹn .

(src)="49"> El hecho de que los padres crean al niño que ha sido víctima de abuso y lo apoyen constituye un gran paso hacia su recuperación .
(trg)="61"> Bó bá sì ṣẹlẹ̀ pé wọ́n bá ọmọdé kan ṣèṣekúṣe , báwọn òbí ò bá ṣáà ti ka ọmọ náà sí onírọ́ tí wọn ò sì jáwọ́ lọ́rọ̀ ẹ̀ , ó máa tètè bọ̀ sípò .

(src)="50"> Sea la primera línea de defensa
(trg)="62"> Kọ́ Ọmọ Ẹ Lóhun Tó Yẹ Kó Mọ̀ Nípa Ìbọ́mọdé - Ṣèṣekúṣe

(src)="51"> Una obra de consulta especializada contiene la siguiente declaración de un convicto por abuso : “ Tráiganme un niño que no sepa nada de sexo , y les presentaré a la próxima víctima ” .
(trg)="63"> A rí ohun tí abọ́mọdé - ṣèṣekúṣe kan tí wọ́n ti dájọ́ fún sọ nínú ìwé kan tá a ti ṣèwádìí .
(trg)="64"> Ó sọ pé : “ Bí mo bá rí ọmọdé kan tí kò mọ ohunkóhun nípa ìbálòpọ̀ , ọwọ́ mi ti ba ohun tí mò ń wá nìyẹn . ”

(src)="52"> Estas escalofriantes palabras deben servir de aviso a los padres .
(trg)="65"> Ìránnilétí pàtàkì lọ̀rọ̀ tí ń bani lẹ́rù yìí jẹ́ fáwọn òbí .

(src)="53"> Un niño ignorante en materia sexual es mucho más fácil de engañar .
(trg)="66"> Ó máa ń rọrùn fáwọn abọ́mọdé - ṣèṣekúṣe láti tan àwọn ọmọ tí ò bá mọ ohunkóhun nípa ìbálòpọ̀ jẹ .

(src)="54"> La Biblia asegura que el conocimiento y la sabiduría pueden librarnos “ del hombre que habla cosas perversas ” .
(trg)="67"> Bíbélì sọ pé ìmọ̀ àti ọgbọ́n lè gbà wá “ lọ́wọ́ ẹni tí ń sọ àwọn ohun àyídáyidà . ”

(src)="55"> ¿ No es eso lo que usted quiere para sus hijos ?
(trg)="68"> Àbí irú ààbò tó ò ń fẹ́ fọ́mọ ẹ kọ́ nìyẹn ?

(src)="56"> Entonces , como segunda medida preventiva , edúquelos cuanto antes en esta importante cuestión .
(trg)="69"> Yàtọ̀ síyẹn , ọ̀nà pàtàkì kejì tó o lè gbà dáàbò bo ọmọ ẹ ni pé kó o má ṣe fà sẹ́yìn láti máa kọ́ ọ nípa kókó pàtàkì tá à ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yìí .

(src)="57"> Pero ¿ cómo hacerlo ?
(trg)="70"> Ọ̀nà wo lo wá lè gbé e gbà ?

(src)="58"> A muchos padres les resulta embarazoso hablar de sexualidad con los hijos , y más embarazoso aún les resulta a los hijos .
(trg)="71"> Ọ̀pọ̀ òbí lara wọn máa ń kó tìọ̀ láti báwọn ọmọ wọn jíròrò ọ̀ràn ìbálòpọ̀ .

(src)="59"> Como no serán ellos los que saquen a relucir el tema , tome usted la iniciativa .
(trg)="73"> Nítorí náà , ìwọ ni kó o kọ́kọ́ dá ọ̀rọ̀ náà sílẹ̀ .